ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | DÁNÍẸ́LÌ 7-9
Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì Sọ Ìgbà Tí Mèsáyà Máa Dé
Bíi Ti Orí Ìwé
“ÀÁDỌ́RIN Ọ̀SẸ̀” (490 ỌDÚN)
“Ọ̀SẸ̀ MÉJE” (49 ỌDÚN)
455 B.C.E. “Ọ̀rọ̀ náà láti mú Jerúsálẹ́mù padà bọ̀ sípò”
406 B.C.E. Wọ́n tún Jerúsálẹ́mù kọ́
“Ọ̀SẸ̀ MÉJÌ-LÉ-LỌ́GỌ́TA” (434 ỌDÚN)
“Ọ̀SẸ̀ KAN” (7 ỌDÚN)
29 C.E. Mèsáyà dé
33 C.E. Wọ́n “ké” Mèsáyà kúrò
36 C.E. Òpin “àádọ́rin ọ̀sẹ̀”