ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 January ojú ìwé 4
  • Máa Wá Ìjọba Náà Lákọ̀ọ́kọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Máa Wá Ìjọba Náà Lákọ̀ọ́kọ́
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Àdúrà Olúwa
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
  • Jèhófà Ń pèsè Àwọn Ohun Tá a Nílò Lójoojúmọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
  • Ṣé Àdúrà Olúwa Ni Àdúrà Tó Dáa Jù Láti Gbà?
    Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • “Olúwa, Kọ́ Wa Bí A Ṣe Ń Gbàdúrà”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 January ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 6-7

Máa Wá Ìjọba Náà Lákọ̀ọ́kọ́

Nínú àdúrà àwòfiṣàpẹẹrẹ, Jésù jẹ́ kó ṣe kedere pé àwọn ọ̀rọ̀ tó jẹ mọ́ àwọn ohun tí Jèhófà fẹ́ ṣe àti Ìjọba rẹ̀ ló yẹ ká fi sípò àkọ́kọ́.

6:9-13

  • Jésù wà lórí ìtẹ́ lọ́run

    Orúkọ Ọlọ́run

    Ìjọba Ọlọ́run

    Ohun tí Ọlọ́run fẹ́

  • Búrẹ́dì

    Oúnjẹ òòjọ́

    Ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀

    Bá a ṣe máa bọ́ lọ́wọ́ ìdẹwò

Àwọn ohun tó jẹ mọ́ Ìjọba náà tí mo lè gbàdúrà fún:

  • Kí iṣẹ́ ìwàásù máa tẹ̀ síwájú

  • Kí ẹ̀mí mímọ́ Ọlọ́run ran àwọn tí wọ́n ń ṣe inúnibíni sí lọ́wọ́

  • Kí Ọlọ́run bù kún iṣẹ́ tí àwọn tó ń kọ́ ilé fún ètò Ọlọ́run ń ṣe lọ́wọ́ níbì kan tàbí níbi tí wọ́n ti ń ṣe àkànṣe iṣẹ́ ìwàásù

  • Kí Ọlọ́run fún àwọn tó ń mú ipò iwájú ní ọgbọ́n àti agbára láti bójú tó iṣẹ́ wọn

  • Àwọn ohun míì

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́