ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 December ojú ìwé 6
  • Fara Wé Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù Bó O Ṣe Ń Wàásù Tó O sì Ń Kọ́ni

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Fara Wé Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù Bó O Ṣe Ń Wàásù Tó O sì Ń Kọ́ni
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹ Di Ọ̀jáfáfá Nínú Bíbá Àwọn Èèyàn Fèrò Wérò
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2005
  • Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀ Màríà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • “Ẹ Máa Ṣe Ohun Gbogbo Nítorí Ìhìn Rere”
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2009
  • “Máa Bá A Lọ ní Fífi Ara Rẹ . . . fún Kíkọ́ni”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2010
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 December ojú ìwé 6
Pọ́ọ̀lù ń wàásù lọ́jà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌṢE 17-18

Fara Wé Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù Bó O Ṣe Ń Wàásù Tó O sì Ń Kọ́ni

17:2, 3, 17, 22, 23

Báwo la ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù?

  • Pọ́ọ̀lù ń wàásù lọ́jà

    A lè fèrò wérò pẹ̀lú àwọn èèyàn tá à ń bá sọ̀rọ̀ látinú Ìwé Mímọ́, ká sì gbé ọ̀rọ̀ wa kalẹ̀ lọ́nà tó máa yé wọn

  • Pọ́ọ̀lù ń wàásù ní òpópónà

    A tún lè lọ wàásù níbi tá a ti máa rí àwọn èèyàn àti nígbà tó ṣeé ṣe ká rí wọn

  • Arákùnrin kan ń lo Bíbélì ọkùnrin kan bó ṣe ń wàásù fún un

    A lè dọ́gbọ́n gbà pẹ̀lú ohun tí onílé gbà gbọ́ ká lè bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ wa látibẹ̀

ṢÀṢÀRÒ LÓRÍ ÌBÉÈRÈ YÌÍ: Ní ìpínlẹ̀ ìwàásù mi, ibo ni mo ti lè rí ọ̀pọ̀ èèyàn, ìgbà wo sì ni mo lè bá wọn?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́