ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 June ojú ìwé 5
  • “Ẹ Gbé Gbogbo Ìhámọ́ra Ogun Láti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Wọ̀”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ẹ Gbé Gbogbo Ìhámọ́ra Ogun Láti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Wọ̀”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Ẹ Gbé Gbogbo Ìhámọ́ra Ọlọrun Wọ̀”
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1992
  • “Ẹ Gbé Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ Ìhámọ́ra Ogun Láti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Wọ̀”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
  • Báa Ṣe Lè Mọ Àìlera Tẹ̀mí Kí A sì Borí Rẹ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1999
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 June ojú ìwé 5
Ọkùnrin kan wọ gbogbo ìhámọ́ra ogun

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÉFÉSÙ 4-6

“Ẹ Gbé Gbogbo Ìhámọ́ra Ogun Láti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Wọ̀”

6:​11-17

Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù fi àwa Kristẹni wé ọmọ ogun kan tó wà lójú ogun. Àwọn “ọmọ ogun ẹ̀mí burúkú” ni ọ̀tá àwa Kristẹni. Lóòótọ́, ó lè jọ bíi pé a ò lágbára tàbí pé a ò lẹ́ni lẹ́yìn, àmọ́ tá a bá “gbé gbogbo ìhámọ́ra ogun láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wọ̀,” Jèhófà máa ràn wá lọ́wọ́ láti jagun náà ní àjà ṣẹ́gun.

Kọ ohun tí ìhámọ́ra kọ̀ọ̀kan jẹ́ àtohun tí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn dúró fún

Àwọn ìhámọ́ra ogun

FI ṢÀṢÀRÒ: Ṣé gbogbo ìhámọ́ra ogun ni mo ní?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́