ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 July ojú ìwé 7
  • Ìfọkànsin Ọlọ́run Tàbí Eré Ìdárayá

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìfọkànsin Ọlọ́run Tàbí Eré Ìdárayá
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Eré Ìdárayá?
    Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé
  • Ó Ha Yẹ Kí N Dara Pọ̀ Mọ́ Ẹgbẹ́ Eléré Ìdárayá Bí?
    Jí!—1996
  • Àwọn Eré Ìdárayá Ẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́ Wọ́n Ha Dára fún Mi Bí?
    Jí!—1996
  • Eré Ìdárayá Àwọn Èwe—Ìwà Ipá Tuntun Tó Ń tàn Kálẹ̀
    Jí!—2002
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 July ojú ìwé 7

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ìfọkànsin Ọlọ́run Tàbí Eré Ìdárayá

Ọmọbìnrin kan mú ohun tí wọ́n fi ń gbá tẹní ìsì dání, ọmọkùnrin kan mú ohun tí wọ́n fi ń gbá bọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ dání, ọmọkùnrin mí ì tún mú kóńdó tí wọ́n fi ń gbá baseball dání

Ṣé àǹfààní wà nínú kéèyàn máa ṣeré ìdárayá? Bẹ́ẹ̀ ni, àmọ́ bíńtín ló jẹ́ tá a bá fi wéra pẹ̀lú àǹfààní tá a máa rí tá a bá ń ṣe àwọn nǹkan tó máa jẹ́ ká sún mọ́ Jèhófà. (1Ti 4:8) Torí náà, ó yẹ kí àwa Kristẹni ní èrò tó tọ́ nípa eré ìdárayá.

WO FÍDÍÒ ERÉ OJÚ PÁTÁKÓ NÁÀ OHUN TÓ YẸ KÓ O MỌ̀ NÍPA ERÉ ÌDÁRAYÁ, KÓ O SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  1. Àwọn ọmọkùnrin kan jọ ń wa ọkọ̀ ojú omi

    1. Àwọn nǹkan wo la lè rí kọ́ látinú eré ìdárayá?

  2. Àwọn nǹkan tí ọmọkùnrin kan fẹ́ fi ṣeré ìmárale dà lé e lórí

    2. Kí ni àwọn nǹkan mẹ́ta tó máa pinnu bóyá ó máa dáa ká ṣeré ìdárayá kan tàbí ká má ṣe é?

  3. Ọmọbìnrin kan tó wọ ohun tí wọ́n máa ń wọ̀ sọ́wọ́ láti fi jà ń bínú

    3. Báwo ni Sáàmù 11:5 ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ láti mọ irú eré ìdárayá tó yẹ ká ṣe?

  4. Ọmọkùnrin onígbèéraga kan ń fọ́nnu sí ọmọkùnrin méjì mí ì

    4. Báwo la ṣe lè fi Fílípì 2:3 àti Òwe 16:18 sílò nípa ọ̀nà tá à ń gbà ṣeré ìdárayá?

  5. Ọmọbìnrin kan ń sùn nígbà tí ìpàdé ń lọ lọ́wọ́

    5. Nígbà tá a bá ń ṣe eré ìdárayá tàbí tá à ń wò ó, báwo ni Fílípì 1:10 ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ láti má ṣe lo àkókò tó pọ̀ jù nídìí ẹ̀?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́