ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | HÉBÉRÙ 1-3
Nífẹ̀ẹ́ Òdodo, Kórìíra Ìwà Tí Kò Bófin Mu
Jésù nífẹ̀ẹ́ òdodo, ó sì kórìíra ohunkóhun tó máa múnú bí Jèhófà.
Báwo làwa náà ṣe lè nífẹ̀ẹ́ òdodo bíi ti Jésù . . .
nígbà tá a bá dojú kọ ìdẹwò láti wo ìṣekúṣe?
tí wọ́n bá yọ ẹnì kan lẹ́gbẹ́ nínú ìdílé mi?