ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | HÉBÉRÙ 9-10
“Òjìji Àwọn Nǹkan Rere Tó Ń Bọ̀”
Àgọ́ ìjọsìn ṣàpẹẹrẹ ètò tí Ọlọ́run ṣe láti gba aráyé sílẹ̀ lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ nípasẹ̀ ìràpadà. Nínú àwòrán yìí, a máa rí nǹkan mẹ́rin tó wà nínú àgọ́ ìjọsìn àtohun tí wọ́n ṣàpẹẹrẹ, kọ nọ́ńbà ohun tí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn dúró fún síwájú rẹ̀.
|
|