ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 JÒHÁNÙ 1-5
Ẹ Má Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Ayé Tàbí Àwọn Nǹkan Tó Wà Nínú Ayé
Sátánì máa ń lo àwọn nǹkan mẹ́ta táyé ń gbé lárugẹ yìí kó lè mú ká jìnnà sí Jèhófà. Báwo lo ṣe lè ṣàlàyé ẹ̀ fẹ́nì kan?
“Ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara”
“Ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ojú”
“Fífi ohun ìní ẹni ṣe àṣehàn”