ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 November ojú ìwé 3
  • Yẹra fún Ẹ̀mí Ayé Tó O Bá Ń Ṣètò Ìgbéyàwó

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Yẹra fún Ẹ̀mí Ayé Tó O Bá Ń Ṣètò Ìgbéyàwó
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ṣe Ohun Tó Máa Jẹ́ Kí Ayọ̀ àti Iyì Ọjọ́ Ìgbéyàwó Rẹ Pọ̀ Sí I
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2006
  • Àwọn Ìgbéyàwó Aláyọ̀ Tí Ń bọlá Fún Jèhófà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2000
  • Ayẹyẹ Ìgbéyàwó Tí Ń Bọlá fún Jèhófà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1997
  • Báwo Ni Ìgbéyàwó Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣe Máa Ń Rí?
    Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Sábà Máa Ń Béèrè Nípa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 November ojú ìwé 3
Fọ́tò ìdílé kan lọ́jọ́ ìgbéyàwó

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Yẹra fún Ẹ̀mí Ayé Tó O Bá Ń Ṣètò Ìgbéyàwó

Àwọn Kristẹni tó fẹ́ ṣègbéyàwó ní ọ̀pọ̀ ìpinnu láti ṣe. Ó lè máa ṣe wọ́n bíi kí wọ́n filé pọntí fọ̀nà rokà lọ́jọ́ ìgbéyàwó wọn bíi táwọn míì. Àwọn ẹbí àtàwọn ọ̀rẹ́ tiẹ̀ lè bẹ̀rẹ̀ sí í mú onírúurú àbá wá nípa bó ṣe yẹ kí ìgbéyàwó náà rí. Àmọ́ àwọn ìlànà Bíbélì wo ló máa ran àwọn tó fẹ́ ṣègbéyàwó náà lọ́wọ́, kí wọ́n lè ṣètò ọjọ́ ayọ̀ wọn lọ́nà táá múnú wọn dùn, tí ẹ̀rí ọkàn wọn ò sí ní máa dá wọn lẹ́bi?

WO FÍDÍÒ NÁÀ ÌGBÉYÀWÓ TÓ NÍ ỌLÁ LÓJÚ JÈHÓFÀ, LẸ́YÌN NÁÀ, DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Báwo làwọn ìlànà Bíbélì yìí ṣe ran Nick àti Juliana lọ́wọ́?

    • 1Kọ 10:31

    • 1Jo 2:15, 16

    • Ga 5:19-21

    • 1Ti 2:9

  • Kí nìdí tó fi yẹ káwọn tó fẹ́ ṣègbéyàwó fi arákùnrin tí òtítọ́ jinlẹ̀ nínú rẹ̀ ṣe “olùdarí àsè”?—Jo 2:9, 10.

  • Kí ló ran Nick àti Juliana lọ́wọ́ láti ṣe ìpinnu tó tọ́ nípa ètò ìgbéyàwó wọn?

  • Ta ló máa pinnu bí gbogbo ètò ìgbéyàwó náà ṣe máa rí?​—w06 10/15 25 ¶10.

Àwòrán: Àwòrán látinú fídíò ‘Ìgbéyàwó Tó Ní Ọlá Lójú Jèhófà.’ Nick àti Juliana ń ṣètò ìgbéyàwó, wọ́n sì ní ọ̀pọ̀ ìpinnu láti ṣe. 1. Àwọn méjèèjì ń gbàdúrà láyè ara wọn. 2. Fóònù àti ìtẹ̀jáde tí wọ́n fi ń ṣèwádìí. 3. Wọ́n ń sọ ohun tí wọ́n fẹ́ ṣe fáwọn òbí wọn. 4. Àwọn àtàwọn míì nínú ìdílé wọn jọ ń ṣètò ìwé ìkésíni tí wọ́n fẹ́ pín.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́