ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 46-47
Jèhófà Pèsè Oúnjẹ Lásìkò Ìyàn
Ìyàn tẹ̀mí mú gan-an nínú ayé lónìí. (Emọ 8:11) Àmọ́ Jèhófà ń lo Jésù Kristi láti pèsè ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ oúnjẹ tẹ̀mí tó ń ṣara lóore.
Àwọn ìtẹ̀jáde tó dá lórí Bíbélì
Àwọn ìpàdé ìjọ
Àwọn àpéjọ àyíká àti agbègbè
Àwọn àtẹ́tísí
Àwọn fídíò
Ìkànnì JW.ORG
Ètò JW Broadcast
Àwọn nǹkan wo ni mo ti pa tì kí n lè máa gbádùn gbogbo oúnjẹ tẹ̀mí tí Jèhófà ń pèsè?