ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 November ojú ìwé 5
  • Ohun Tá A Mú Wá Láti Dúpẹ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Mú Wá Láti Dúpẹ́
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹ Máa Fọpẹ́ Hàn
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2004
  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Fi Ìmoore Hàn?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2019
  • Àwọn Ohun Tá A Rí Kọ́ Nínú Ìwé Léfítíkù
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2019
  • Lórí Tábìlì Wo Ni Ìwọ Ti Ń Jẹun?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1994
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 November ojú ìwé 5
Ìdílé kan ń jẹ lára ẹran tí wọ́n fi rú ẹbọ ìrẹ́pọ̀.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÉFÍTÍKÙ 6-7

Ohun Tá A Mú Wá Láti Dúpẹ́

7:11-15, 20

Ẹbọ ìrẹ́pọ̀ táwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa ń rú jẹ́ ká rí ìdí tó fi ṣe pàtàkì ká máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà, ká sì máa fi hàn nínú ìwà wa pé a mọyì ohun tí Jèhófà ń ṣe fún wa.​—Flp 4:6, 7; Kol 3:15.

  • Tá a bá ń gbàdúrà, àwọn nǹkan wo la lè dúpẹ́ fún?​—1Tẹ 5:17, 18

  • Kí nìdí tó fi yẹ ká máa fi hàn pé a mọyì ohun tí Jèhófà ń ṣe fún wa?

  • Báwo lẹnì kan ṣe lè máa jẹun lórí “tábìlì àwọn ẹ̀mí èṣù,” báwo nìyẹn sì ṣe máa fi hàn pé ẹni náà ò mọyì ohun tí Jèhófà ń ṣe?​—1Kọ 10:20, 21

Obìnrin kan gbojú sókè, ó sì ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́