ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 January ojú ìwé 12
  • Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Wà Létòlétò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Wà Létòlétò
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹnì Kan Lè Ṣe Ọ̀pọ̀ Èèyàn Láǹfààní
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Bí Jèhófà Ṣe Ń Darí Àwọn Èèyàn Rẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ṣé O Máa Ń Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Àṣìṣe Ẹ?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 January ojú ìwé 12

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Wà Létòlétò

[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Nọ́ńbà.]

Wọ́n pín àgọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí ẹ̀yà mẹ́ta-mẹ́ta (Nọ 1:52, 53; w94 12/1 9 ¶4)

Ó ṣeé ṣe kí gbogbo wọn lápapọ̀ tó mílíọ̀nù mẹ́ta tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ (Nọ 2:32, 33; it-1 397 ¶4)

Jèhófà fẹ́ káwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa wà létòlétò bí wọ́n ṣe ń jọ́sìn òun, wọ́n sì ṣe bẹ́ẹ̀. Ohun kan náà là ń ṣe lónìí.​—1Kọ 14:33, 40.

Bí ibùdó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe rí tá a bá wò ó látòkè. Àgọ́ ìjọsìn ló wà láàárín. Ìtòsí àgọ́ ìjọsìn làwọn ọmọ Léfì pàgọ́ sí: Àwọn ọmọ Áárónì wà ní ìlà oòrùn, àwọn ọmọ Kóhátì wà ní gúúsù, àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì wà ní ìwọ̀ oòrùn, àwọn ọmọ Mérárì sì wà ní àríwá. Àwọn ẹ̀yà méjìlá tó kù ò sí nítòsí àgọ́ ìjọsìn. Àwọn ẹ̀yà Ísákà, Júdà àti Sébúlúnì ló wà ní apá ìlà oòrùn. Gádì, Rúbẹ́nì àti Síméónì wà ní gúúsù. Bẹ́ńjámínì, Éfúrémù àti Mánásè wà ní ìwọ̀ oòrùn. Náfútálì, Dánì àti Áṣérì sì wà ní àríwá.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Kí ni mo lè ṣe láti fi hàn pé mò ń fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ètò Ọlọ́run?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́