ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 January ojú ìwé 16
  • Ṣé Wàá Fẹ́ Ṣe Aṣáájú-Ọ̀nà Olùrànlọ́wọ́ Lóṣù March Tàbí April?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé Wàá Fẹ́ Ṣe Aṣáájú-Ọ̀nà Olùrànlọ́wọ́ Lóṣù March Tàbí April?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ṣètò Báyìí Láti Ṣe Púpọ̀ Sí I Lẹ́nu Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2012
  • A Ní Àǹfààní Púpọ̀ Sí I Láti Yin Jèhófà
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2013
  • A Ń Fẹ́—30,000 Aṣáájú Ọ̀nà Olùrànlọ́wọ́
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—1997
  • Ẹ Polongo Àwọn Ìtayọlọ́lá Jèhófà Kárí Ayé
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2007
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 January ojú ìwé 16
Àwọn arákùnrin kan ń gbé ohun tá a fi ń pàtẹ ìwé jáde látinú Gbọ̀ngàn Ìjọba.

“Ìfẹ́ tí Kristi ní sọ ọ́ di dandan fún wa.”​—2Kọ 5:14

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ṣé Wàá Fẹ́ Ṣe Aṣáájú-Ọ̀nà Olùrànlọ́wọ́ Lóṣù March Tàbí April?

Ṣé wàá fẹ́ ṣe púpọ̀ sí i lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Jèhófà ní àkókò Ìrántí Ikú Kristi? (2Kọ 5:14, 15) Lóṣù March àti April, àwọn tó bá fẹ́ ṣe aṣáájú-ọ̀nà olùrànlọ́wọ́ lè yàn láti ròyìn ọgbọ̀n (30) wákàtí tàbí àádọ́ta (50). Tó bá máa rọrùn fún ẹ láti lọ́wọ́ nínú iṣẹ́ pàtàkì yìí, gba fọ́ọ̀mù aṣáájú-ọ̀nà olùrànlọ́wọ́, kọ ọ̀rọ̀ kún inú rẹ̀, kó o sì fún Ìgbìmọ̀ Iṣẹ́ Ìsìn Ìjọ yín. Wọ́n máa ka orúkọ àwọn tó bá fẹ́ ṣe aṣáájú-ọ̀nà olùrànlọ́wọ́ fún ìjọ, ìyẹn á sì jẹ́ kí àwọn ará túbọ̀ jáde láàárín oṣù yẹn láti ràn wọ́n lọ́wọ́ lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù. Ẹ jẹ́ kí gbogbo wa lo àǹfààní àsìkò Ìrántí Ikú Kristi yìí láti fún ara wa níṣìírí, ká sì tún já fáfá lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù.​—1Tẹ 5:11.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́