ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ọlọ́run Ló Ni Ìdájọ́”
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Diutarónómì.]
Àwọn alàgbà gbọ́dọ̀ máa “fi òdodo ṣèdájọ́” (Di 1:16; w96 3/15 23 ¶1)
Àwọn alàgbà “ò gbọ́dọ̀ gbè sápá kan nínú ìdájọ́” (Di 1:17; w02 8/1 10 ¶4)
Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọyì ohun táwọn alàgbà ń ṣe?—Heb 13:17; Jem 5:13-15