ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 March ojú ìwé 6
  • “Ọkàn Mi Á Máa Wà Níbẹ̀ Nígbà Gbogbo”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ọkàn Mi Á Máa Wà Níbẹ̀ Nígbà Gbogbo”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Ẹ Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Jèhófà Ọlọ́run Yín”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • B8 Tẹ́ńpìlì Tí Sólómọ́nì Kọ́
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • Tá A Bá Tẹ̀ Lé Ìmọ̀ràn Tó Dáa Ó Máa Ṣe Wá Láǹfààní
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Wọ́n Fi Gbogbo Ọkàn sí Iṣẹ́ Ilé Náà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 March ojú ìwé 6

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Ọkàn Mi Á Máa Wà Níbẹ̀ Nígbà Gbogbo”

Jèhófà yan tẹ́ńpìlì náà fún ara ẹ̀ (2Kr 7:11, 12)

Jèhófà sọ pé ọkàn òun á máa wà níbẹ̀ nígbà gbogbo, ìyẹn ni pé á máa kíyè sí àwọn nǹkan tó bá ń ṣẹlẹ̀ níbẹ̀ nítorí orúkọ mímọ́ rẹ̀ (2Kr 7:16; w02 11/15 5 ¶1)

Tí àwọn èèyàn náà ò bá fi “gbogbo ọkàn wọn” rìn níwájú Jèhófà mọ́, ó máa jẹ́ kí wọ́n pa tẹ́ńpìlì náà run (2Kr 6:14; 7:19-21; it-2 1077-1078)

Àwòrán: Ohun tí à ń ṣe nínú ìjọsìn. 1. Arákùnrin kan ń gbàdúrà. 2. Arábìnrin kan ń dáhùn nípàdé. 3. Tọkọtaya kan jọ ń wàásù. 4. Arákùnrin kan ń tọ́jú Gbọ̀ngàn Ìjọba. 5. Arákùnrin kan àti ìyàwó rẹ̀ pẹ̀lú ọmọ méjì jọ ń ṣe ìjọsìn ìdílé. 6. Arábìnrin kan ń ka Bíbélì. 7. Arábìnrin kan ń fi owó sínú àpótí ọrẹ.

Lásìkò tí wọ́n ń ya tẹ́ńpìlì náà sí mímọ́, àwọn èèyàn náà rò pé àwọn á máa fi gbogbo ọkàn wọn ṣe ìjọsìn Jèhófà. Àmọ́, ó bani nínú jẹ́ pé kò pẹ́ tí ìtara wọn fún ìjọsìn Jèhófà fi bẹ̀rẹ̀ sí í dín kù.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Báwo ni mo ṣe lè fi hàn pé mo ka ìjọsìn Jèhófà sí pàtàkì?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́