ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 November ojú ìwé 4
  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Èdèkòyédè Kan Tó Wáyé

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Èdèkòyédè Kan Tó Wáyé
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìmọ̀ràn Tí Jóṣúà Fún Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kẹ́yìn
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Máa Fi Gbogbo Ọkàn Rẹ Tẹ̀ Lé Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Ní Ìtẹ́lọ́rùn, Ká sì Mọ̀wọ̀n Ara Wa?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Jèhófà Jà Fáwọn Ọmọ Ísírẹ́lì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 November ojú ìwé 4
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó ń gbé apá ìlà oòrùn Jọ́dánì ń fi ohùn pẹ̀lẹ́ dáhùn nígbà táwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó kù ń fẹ̀sùn kàn wọ́n.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Èdèkòyédè Kan Tó Wáyé

Àwọn ẹ̀yà tó ń gbé apá ìlà oòrùn Jọ́dánì kọ́ pẹpẹ kan tó tóbi, tó sì fani mọ́ra (Joṣ 22:10)

Àwọn ẹ̀yà tó kù fẹ̀sùn kàn wọ́n pé wọ́n ti fi Jèhófà sílẹ̀ (Joṣ 22:12, 15, 16; w06 4/15 5 ¶3)

Àwọn ẹ̀yà tí wọ́n fẹ̀sùn kàn dáhùn lọ́nà pẹ̀lẹ́, ìyẹn sì mú kọ́rọ̀ náà yanjú láì sógun (Joṣ 22:21-30; w08 11/15 18 ¶5)

Kí la rí kọ́ nínú ìtàn yìí nípa ohun tó yẹ ká ṣe tí wọ́n bá fẹ̀sùn èké kàn wá àti ìdí tó fi yẹ ká mọ kúlẹ̀kúlẹ̀ nípa ọ̀rọ̀ kan ká tó gbà pé bọ́rọ̀ náà ṣe rí nìyẹn?​—Owe 15:1; 18:13.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́