ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 May ojú ìwé 5
  • “Ìfẹ́ . . . Kì Í Yọ̀ Lórí Àìṣòdodo”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ìfẹ́ . . . Kì Í Yọ̀ Lórí Àìṣòdodo”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìfẹ́ Ni A Fi Ń Dá Àwọn Kristẹni Tòótọ́ Mọ̀—Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Òtítọ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Wọ́n Di Ọ̀rẹ́ Tímọ́tímọ́
    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn
  • Jónátánì—“Bá Ọlọ́run Ṣiṣẹ́ Pọ̀”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
  • Jónátánì Nígboyà, Ó sì Jẹ́ Adúrótini
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 May ojú ìwé 5

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

“Ìfẹ́ . . . Kì Í Yọ̀ Lórí Àìṣòdodo”

Àwa Kristẹni tòótọ́ máa ń sapá láti jẹ́ kí ìfẹ́ sún wa ṣe gbogbo ohun tá a bá ń ṣe. Bíbélì jẹ́ ká mọ̀ pé ìfẹ́ “kì í yọ̀ lórí àìṣòdodo.” (1Kọ 13:4, 6) Torí náà, a máa ń yẹra fún eré ìnàjú tó bá ń gbé ìṣekúṣe àti ìwà ipá lárugẹ. Bákan náà, a kì í yọ̀ tí nǹkan burúkú bá ṣẹlẹ̀ sáwọn míì, títí kan àwọn tó ti ṣe ohun tó dùn wá.​—Owe 17:5.

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ MÁ GBÀGBÉ OHUN TÍ ÌFẸ́ MÁA Ń ṢE​—KÌ Í YỌ̀ LÓRÍ ÀÌṢÒDODO, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Kí ni Dáfídì ṣe nígbà tó gbọ́ pé Sọ́ọ̀lù àti Jónátánì ti kú?

  • Irú orin wo ni Dáfídì kọ fún Sọ́ọ̀lù àti Jónátánì?

  • Kí nìdí tí Dáfídì ò fi yọ̀ nígbà tó gbọ́ pé Sọ́ọ̀lù kú?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́