ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 November ojú ìwé 2
  • Àwọn Tó Wà Pẹ̀lú Wa Pọ̀ Ju Àwọn Tó Wà Pẹ̀lú Wọn

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Tó Wà Pẹ̀lú Wa Pọ̀ Ju Àwọn Tó Wà Pẹ̀lú Wọn
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àwọn Ọmọ Ogun Jèhófà
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • Èlíṣà Rí Kẹ̀kẹ́ Ẹṣin Oníná—Ṣé Ìwọ Náà Rí I?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
  • “Gbé Ọmọ Rẹ”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 November ojú ìwé 2
Ẹnu ya ìránṣẹ́ Èlíṣà nígbà tí Èlíṣà fi àwọn ẹṣin àti àwọn kẹ̀kẹ́ ogun oníná tó yí àwọn ọmọ ogun Síríà ká hàn án.

Èlíṣà sọ fún ìránṣẹ́ rẹ̀ pé: “Àwọn tó wà pẹ̀lú wa pọ̀ ju àwọn tó wà pẹ̀lú wọn.”​—2Ọb 6:16

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Àwọn Tó Wà Pẹ̀lú Wa Pọ̀ Ju Àwọn Tó Wà Pẹ̀lú Wọn

Àwọn ọmọ ogun ọ̀tá yí Èlíṣà àti ìránṣẹ́ rẹ̀ ká (2Ọb 6:13, 14; it-1 716 ¶4)

Èlíṣà ò bẹ̀rù, ó sì fún ìránṣẹ́ rẹ̀ lókun (2Ọb 6:15-17; w13 8/15 30 ¶2; wo àwòrán iwájú ìwé)

Jèhófà dáàbò bo Èlíṣà àti ìránṣẹ́ rẹ̀ lọ́nà ìyanu (2Ọb 6:18, 19; it-1 343 ¶1)

Jésù àtàwọn ọmọ ogun rẹ̀ wà lọ́run, wọ́n sì ń wò bí àwọn ọlọ́pàá àtàwọn sójà ṣe ń ya wọ àdúgbò kan. Arákùnrin kan ń mú àwọn ará méjì wọnú ilé rẹ̀.

Àwọn ọ̀tá wa kéré sí Jèhófà gan-an. Ká sọ pé a lè rí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́run, ká sì rí bí Jèhófà ṣe ń lo àwọn áńgẹ́lì láti dáàbò bo àwa èèyàn rẹ̀, àá rí i pé kò sídìí fún wa láti bẹ̀rù.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́