ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 November ojú ìwé 7
  • Jèhófà Fìyà Jẹ Obìnrin Burúkú Kan

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà Fìyà Jẹ Obìnrin Burúkú Kan
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹgbẹ́ Búburú Ò Jẹ́ Kí Jèhóáṣì Sin Jèhófà Mọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • “Gbogbo Ilé Áhábù Ló Máa Ṣègbé”—2Ọb 9:8
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Jèhóádà Nígboyà
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • Jèhófà Ṣe Ohun Tó Dà Bíi Pé Kò Ṣeé Ṣe
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 November ojú ìwé 7

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Fìyà Jẹ Obìnrin Burúkú Kan

Ataláyà pa àwọn ọmọ ọba kó lè máa ṣàkóso ilẹ̀ Júdà (2Ọb 11:1; it-1 209; wo àtẹ náà “‘Gbogbo Ilé Áhábù Ló Máa Ṣègbé’​—2Ọb 9:8”)

Jèhóṣébà gbé Jèhóáṣì tó jẹ́ ọmọ ọba pa mọ́ (2Ọb 11:2, 3)

Jèhóádà Àlùfáà Àgbà fi Jèhóáṣì jọba, ó sì pa Ataláyà tó ṣeé ṣe kó jẹ́ ẹnì kan ṣoṣo tó ṣẹ́ kù nílé Áhábù (2Ọb 11:12-16; it-1 209)

ṢÀṢÀRÒ LÓRÍ ÌBÉÈRÈ YÌÍ: Báwo ni ìtàn yìí ṣe jẹ́ kó túbọ̀ dá wa lójú pé òótọ́ lohun tó wà ní Òwe 11:21 àti Oníwàásù 8:12, 13?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́