ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 November ojú ìwé 15
  • Àdúrà Wa Ṣeyebíye Lójú Jèhófà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àdúrà Wa Ṣeyebíye Lójú Jèhófà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Sún Mọ́ Ọlọ́run Nípasẹ̀ Àdúrà
    Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an?
  • O Ha ‘Ń pèsè Àdúrà Rẹ Bí Tùràrí’ bí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1999
  • Adura Awọn Wo Ni A Ndahun?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1991
  • Bá a Ṣe Lè Bá “Olùgbọ́ Àdúrà” Sọ̀rọ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2006
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 November ojú ìwé 15
Àwòrán: Àwọn ará lọ́kùnrin àti lóbìnrin kárí ayé ń gbàdúrà. 1. Ọmọbìnrin kan àti ìyá rẹ̀ ń gbàdúrà lórí bẹ́ẹ̀dì lásìkò tí wọ́n fẹ́ sùn. 2. Ọkọ kan ń gbàdúrà pẹ̀lú ìyàwó rẹ̀ tó wà nílé ìwòsàn. 3. Arákùnrin kan ń gbàdúrà nígbà tó gbafẹ́ jáde. 4. Arábìnrin kan tí ìrònú bá ń gbàdúrà. 5. Arábìnrin kan ń gbàdúrà kó tó bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́. 6. Arákùnrin kan ní ilẹ̀ tí nǹkan ò ti fi bẹ́ẹ̀ rọ̀ṣọ̀mù ń gbàdúrà. 7. Àwọn òbí kan ń gbàdúrà pẹ̀lú ọmọbìnrin wọn kí wọ́n tó jẹun.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Àdúrà Wa Ṣeyebíye Lójú Jèhófà

Àwọn àdúrà tí Jèhófà nífẹ̀ẹ́ sí dà bíi tùràrí olóòórùn dídùn tí wọ́n máa ń sun nínú tẹ́ńpìlì nígbà gbogbo. (Sm 141:2) Tá a bá ń jẹ́ kí Jèhófà mọ bá a ṣe nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ tó, tá à ń sọ ohun tó ń jẹ wá lọ́kàn àtohun tó wù wá, tá a sì ń bẹ̀ ẹ́ pé kó tọ́ wa sọ́nà, ìyẹn á fi hàn pé a mọyì àǹfààní tá a ní láti jẹ́ ọ̀rẹ́ rẹ̀. Òótọ́ ni pé apá pàtàkì lára ìjọsìn wa ni Jèhófà ka àwọn àdúrà tá a máa ń gbà láwọn ìpàdé wa sí. Àmọ́ inú rẹ̀ máa ń dùn gan-an tá a bá tú ọkàn wa jáde sí i nínú àdúrà tá a dá gbà, tá a sì lo àkókò tó pọ̀ láti bá a sọ̀rọ̀.—Owe 15:8.

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ MI Ò FỌ̀RỌ̀ ÀDÚRÀ ṢERÉ, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Àwọn àǹfààní iṣẹ́ ìsìn wo ni Arákùnrin Johnson ti ní?

  • Báwo ni Arákùnrin Johnson ṣe fi hàn pé òun ò fọ̀rọ̀ àdúrà ṣeré?

  • Kí lo rí kọ́ látinú ìrírí Arákùnrin Johnson?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́