ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 May ojú ìwé 9
  • Jèhófà Ni “Bàbá Àwọn Ọmọ Aláìníbaba”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà Ni “Bàbá Àwọn Ọmọ Aláìníbaba”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Ṣe Àwọn Ìpinnu Tó Fi Hàn Pé O Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ẹ Fi Ìlànà Bíbélì Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Kí Wọn Lè Ṣàṣeyọrí
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • “Ẹ Fúnra Yín Yan Ẹni Tí Ẹ Fẹ́ Máa Sìn”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2025
  • Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Kó O sì Gbà Pé Àwọn Nǹkan Kan Wà Tó Ò Mọ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2025
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 May ojú ìwé 9
Ọ̀dọ́kùnrin tí àwòrán ẹ̀ wà nínú àpilẹ̀kọ “O Lè Sin Jèhófà Táwọn Òbí Ẹ Ò Bá Tiẹ̀ Ṣe Bẹ́ẹ̀” ń bá arákùnrin àgbàlagbà kan sọ̀rọ̀ bí wọ́n ṣe jọ ń ṣiṣẹ́ lóde ìwàásù.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Jèhófà Ni “Bàbá Àwọn Ọmọ Aláìníbaba”

Ọdọọdún ni àìmọye àwọn ọ̀dọ́ ń pinnu láti di ọ̀rẹ́ Jèhófà. (Sm 110:3) Jèhófà mọyì ẹnì kọ̀ọ̀kan yín, ó sì nífẹ̀ẹ́ yín gan-an. Ó mọ àwọn nǹkan tí ẹ̀ ń bá yí, ó sì ti ṣèlérí pé òun máa ràn yín lọ́wọ́ kẹ́ ẹ lè jẹ́ olóòótọ́ sí òun. Tó bá jẹ́ pé òbí kan ṣoṣo ló ń tọ́ ẹ, rántí pé Jèhófà ni “Bàbá àwọn ọmọ aláìníbaba.” (Sm 68:5) Torí náà, láìka ti pé òbí kan ló ń tọ́ ẹ, Jèhófà máa dá ẹ lẹ́kọ̀ọ́, wàá sì ṣàṣeyọrí.​—1Pe 5: 10.

Apá kan nínú fídíò “Ìgbàgbọ́ Ń Mú Kí Wọ́n Ja Àjàṣẹ́gun​—Àwọn Tí Òbí Kan Ṣoṣo Tọ́.” Tammy Ludlow.

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ ÌGBÀGBỌ́ Ń MÚ KÍ WỌ́N JA ÀJÀṢẸ́GUN​—ÀWỌN TÍ ÒBÍ KAN ṢOṢO TỌ́, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Kí lo rí kọ́ lára Tammy, Charles àti Jimmy?

  • Kí ni Sáàmù 27:10 sọ tó lè fi àwọn tí òbí kan ṣoṣo ń tọ́ lọ́kàn balẹ̀?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́