ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 September ojú ìwé 14
  • Ohun Mẹ́ta Táá Jẹ́ Ká Ní Ọgbọ́n, Kó sì Ṣe Wá Láǹfààní

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Mẹ́ta Táá Jẹ́ Ká Ní Ọgbọ́n, Kó sì Ṣe Wá Láǹfààní
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kò Nira Jù Láti Sin Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ǹjẹ́ O Rántí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2021
  • “Kí Ni Jèhófà Ọlọ́run Rẹ Fẹ́ Kó O Ṣe?”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Fara Wé Bí Jèhófà Ṣe Ń Lo Ọlá Àṣẹ Rẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 September ojú ìwé 14

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ohun Mẹ́ta Táá Jẹ́ Ká Ní Ọgbọ́n, Kó sì Ṣe Wá Láǹfààní

Máa kíyè sí àwọn ohun tí Ọlọ́run dá (Job 12:​7-9; w09 4/15 6 ¶17)

Mú àwọn tí òtítọ́ jinlẹ̀ nínú wọn lọ́rẹ̀ẹ́ (Job 12:12; w21.06 10-11 ¶10-12)

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn ìlànà Ọlọ́run, kó o sì máa fi wọ́n sílò nígbèésí ayé rẹ (Job 12:16; it-2 1190 ¶2)

Ìdílé kan ń gbádùn ara wọn lábẹ́ igi, tọkọtaya àgbàlagbà kan sì wà pẹ̀lú wọn. Wọ́n ń wo ẹyẹ tó wà lórí igi.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Bí mo ṣe ń wà pẹ̀lú àwọn Kristẹni tí òtítọ́ jinlẹ̀ nínú wọn, kí ni mo ti rí kọ́ lára wọn?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́