ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 November ojú ìwé 16
  • Ètò Tá A Ṣe Láti Tu Àwọn Tó Wà ní Bẹ́tẹ́lì Nínú

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ètò Tá A Ṣe Láti Tu Àwọn Tó Wà ní Bẹ́tẹ́lì Nínú
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Ṣe Àwọn Ìpinnu Tó Fi Hàn Pé O Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Jèhófà Ò Ní Fi Wá Sílẹ̀ Láé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2025
  • Máa Rántí Pé Jèhófà Ni “Ọlọ́run Alààyè”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2024
  • Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Kó O sì Gbà Pé Àwọn Nǹkan Kan Wà Tó Ò Mọ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2025
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 November ojú ìwé 16

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ètò Tá A Ṣe Láti Tu Àwọn Tó Wà ní Bẹ́tẹ́lì Nínú

Gbogbo wa la máa ń nílò ìtùnú látìgbàdégbà torí pé kò sẹ́ni tí ìṣòro kì í dé bá. Kódà, àwọn tí òtítọ́ jinlẹ̀ nínú wọn àtàwọn tó ní àǹfààní iṣẹ́ ìsìn tó pọ̀ nínú ètò Ọlọ́run máa ń rẹ̀wẹ̀sì nígbà míì. (Job 3:​1-3; Sm 34:19) Kí la lè kọ́ látinú ètò tá a ṣe láti máa tu àwọn tó wà ní Bẹ́tẹ́lì nínú?

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ “GBẸ́KẸ̀ LÉ ỌLỌ́RUN,” KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Àwọn ìṣòro wo làwọn tó wà ní Bẹ́tẹ́lì máa ń ní?

  • Àwọn nǹkan mẹ́rin wo la máa ń ṣe láti tù wọ́n nínú?

  • Àǹfààní wo làwọn arákùnrin tó ń tu àwọn míì nínú ń rí?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́