ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 November ojú ìwé 13
  • Ohun Tí Mo Lè Ṣe Táá Jẹ́ Ká Túbọ̀ Lórúkọ Rere

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tí Mo Lè Ṣe Táá Jẹ́ Ká Túbọ̀ Lórúkọ Rere
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Ṣe Àwọn Ìpinnu Tó Fi Hàn Pé O Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Máa Ṣàkọsílẹ̀ Ìtẹ̀síwájú Rẹ
    Tẹra Mọ́ Kíkàwé Àti Kíkọ́ni
  • Máa Ka Bíbélì Lójoojúmọ́ Kó O Lè Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Kó O sì Gbà Pé Àwọn Nǹkan Kan Wà Tó Ò Mọ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2025
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 November ojú ìwé 13

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ohun Tí Mo Lè Ṣe Táá Jẹ́ Ká Túbọ̀ Lórúkọ Rere

Àwọn èèyàn máa ń kíyè sí ìwà àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. (1Kọ 4:9) A lè bi ara wa pé, ‘Ṣé ọ̀rọ̀ ẹnu mi àti ìwà mi ń bọlá fún Jèhófà?’ (1Pe 2:12) Ọjọ́ pẹ́ táwọn èèyàn ti mọ̀ pé àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní orúkọ rere, ó sì dájú pé a ò ní fẹ́ ṣe ohunkóhun tó máa ba orúkọ rere wa jẹ́.—Onw 10:1.

Nínú àwọn ipò tá a tò sísàlẹ̀ yìí, kọ ohun tó yẹ kí Kristẹni kan ṣe àti ìlànà Bíbélì tó lè ràn án lọ́wọ́:

  • Ẹnì kan tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà fìbínú sọ̀rọ̀ sí ẹ

  • Tí mọ́tò rẹ bá dọ̀tí, tí ilé rẹ ò ṣeé rí tàbí tí aṣọ ẹ rí wúruwùru

  • Ìjọba ṣòfin kan tó ṣòro fún ẹ láti pa mọ́

Àwòrán: Àwọn apá kan látinú fídíò “A Nífẹ̀ẹ́ Òtítọ́, A Sì Ní Ọ̀wọ̀ Tó Jinlẹ̀ Fún Òtítọ́.” 1. Arákùnrin kan ń ka ìwé atọ́ka kan. 2. Arákùnrin kan àti arábìnrin kan ń ṣàyẹ̀wò àwọn ohun tí wọ́n máa fi ṣèwádìí. 3. Àwọn ìwé atọ́ka tí wọ́n ṣèwádìí nínú ẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ìwé “The Origin of Life​—⁠Five Questions Worth Asking.” 4. Obìnrin kan ń wo ìkànnì jw.org lórí fóònù ẹ̀.

Báwo làwọn tó ń ṣèwádìí ní Ẹ̀ka Ìwé Kíkọ ṣe ń mú ká túbọ̀ ní orúkọ rere?

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ A NÍFẸ̀Ẹ́ ÒTÍTỌ́, A SÌ NÍ Ọ̀WỌ̀ TÓ JINLẸ̀ FÚN ÒTÍTỌ́, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

Kí ló wú ẹ lórí nínú gbogbo ohun tí ètò Ọlọ́run ń ṣe láti rí i dájú pé ohun tó péye tó sì jẹ́ òótọ́ là ń tẹ̀ jáde?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́