ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w23 September ojú ìwé 32
  • Ohun Tó O Lè Fi Ṣèwádìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tó O Lè Fi Ṣèwádìí
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àwọn Nǹkan Tá A Lè Fi Kọ́ Àwọn Ọmọdé
  • Máa Lo Ìkànnì jw.org Lẹ́nu Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ—“Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà”
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
  • Máa Lo Ìkànnì Wa Láti Kọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2013
  • Wàá Rí Ìmọ̀ràn Tó Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Lórí Ìkànnì JW.ORG
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ìwà Àpọ́nlé Ti Dàwátì Nínú Ọ̀pọ̀ Ìdílé!
    Jí!—2024
Àwọn Míì
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
w23 September ojú ìwé 32

Ohun Tó O Lè Fi Ṣèwádìí

Àwọn Nǹkan Tá A Lè Fi Kọ́ Àwọn Ọmọdé

Iṣẹ́ ẹ̀yin òbí ni láti kọ́ àwọn ọmọ yín nípa Jèhófà, iṣẹ́ náà ò sì rọrùn rárá. (Éfé. 6:4) Torí náà, ètò Ọlọ́run tẹ àwọn ìwé, wọ́n ṣe àwọn fídíò àtàwọn orin tẹ́ ẹ lè fi ran àwọn ọmọ yín lọ́wọ́. Báwo lẹ̀yin òbí ṣe máa lo àwọn nǹkan yìí?

  • Lọ wo jw.org. Àwọn fídíò àtàwọn àpilẹ̀kọ tá a ṣe fáwọn ọmọdé wà níbẹ̀.a Kó o lè rí àwọn nǹkan náà, tẹ “Ọmọdé” tàbí “Ọ̀dọ́” sínú àpótí tá a fi ń wá nǹkan.

  • Yan àwọn ohun tó máa ran ọmọ ẹ lọ́wọ́. Àwọn nǹkan tó wà ní abala “Ọmọdé” máa jẹ́ kó o yan ohun tó máa ran ọmọ ẹ lọ́wọ́. Kó o lè rí àwọn nǹkan náà, tẹ “Iṣẹ́ Ìjọsìn Ìdílé” sínú àpótí tá a fi ń wá nǹkan.

  • Ṣàlàyé ẹ̀kọ́ náà fún wọn. Má kàn ní kí ọmọ ẹ máa wo àwọn fídíò náà, kó sì máa kọ̀rọ̀ sínú àwọn eré aláwòrán náà torí pé ó ń dí ẹ lọ́wọ́ tàbí torí pé o ò fẹ́ kó máa fàkókò ṣòfò. Kàkà bẹ́ẹ̀, ṣàlàyé àwọn ẹ̀kọ́ náà fún ọmọ ẹ, kó lè túbọ̀ sún mọ́ Jèhófà.

a Ní báyìí, gbogbo fídíò tá a ṣe fáwọn ọmọdé àtàwọn ọ̀dọ́ ló wà lórí JW Library®, àmọ́ àwọn nǹkan tí wọ́n lè yàwòrán sí tàbí tí wọ́n lè kọ nǹkan sí tó wà níbẹ̀ ò fi bẹ́ẹ̀ pọ̀.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́