September 8 Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ìrànwọ́ Láti Jáwọ́ Nínú Ìwà Ìpáǹle Ṣé Ohun Tó Hàn Sí Ojúyòójú Nìkan Lò Ń Rí? Ìbẹ̀wò sí “Ìlú Tọ́jọ́ Rẹ̀ Pẹ́ Jù Lọ ní Rọ́ṣíà” Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Àwọn Tó Máa Ń Fi Ọ̀ranyàn Báni Tage? Bí Mo Ṣe Sapá Láti Ṣe Yíyàn Tó Bọ́gbọ́n Mu Òkè Ayọnáyèéfín Tẹ́lẹ̀ Rí Di Erékùṣù Tó Pa Rọ́rọ́ Iṣẹ́ Abẹ Láìlo Ẹ̀jẹ̀—Àpẹẹrẹ Kan Tó Yọrí Sí Rere Bí Loida Ṣe Di Ẹni Tó Ń Sọ̀rọ̀ Ìsẹ̀lẹ̀! Àṣàrò Tó Ṣàǹfààní “Ẹyẹ Tó Lẹ́wà Jù Lọ Tó Ń Gbé Inú Igbó” Wíwo Ayé Ìwà Àìláàánú Tí Ènìyàn Ń hù—Yóò Ha Dópin Láé Bí?