Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
September 8, 2000
Ríríran Ré Kọjá Ohun Tó Hàn sí Ojúyòójú Rẹ
Ohun púpọ̀ ló wà tí a kò lè fi ojúyòójú wa rí. Kí ni a ń rí nígbà tí a bá wò ré kọjá ohun tí ẹ̀dá lè fi ojúyòójú rí? Báwo ló ṣe lè nípa lórí ìgbésí ayé rẹ?
3 Ìrànwọ́ Láti Jáwọ́ Nínú Ìwà Ìpáǹle
4 Ṣé Ohun Tó Hàn Sí Ojúyòójú Nìkan Lò Ń Rí?
12 Bí Mo Ṣe Sapá Láti Ṣe Yíyàn Tó Bọ́gbọ́n Mu
16 Òkè Ayọnáyèéfín Tẹ́lẹ̀ Rí Di Erékùṣù Tó Pa Rọ́rọ́
19 Iṣẹ́ Abẹ Láìlo Ẹ̀jẹ̀—Àpẹẹrẹ Kan Tó Yọrí Sí Rere
20 Bí Loida Ṣe Di Ẹni Tó Ń Sọ̀rọ̀
23 Ìsẹ̀lẹ̀!
28 “Ẹyẹ Tó Lẹ́wà Jù Lọ Tó Ń Gbé Inú Igbó”
30 Wíwo Ayé
32 Ìwà Àìláàánú Tí Ènìyàn Ń hù—Yóò Ha Dópin Láé Bí?
Ìbẹ̀wò sí “Ìlú Tọ́jọ́ Rẹ̀ Pẹ́ Jù Lọ ní Rọ́ṣíà” 6
Ìlú Novgorod ti lé ní ẹgbẹ̀rún kan ó lé ọgọ́rùn-ún ọdún. Wo ohun tí wọ́n sọ nípa ibi tí wọ́n sọ pé òun ni ìlú tọ́jọ́ rẹ̀ pẹ́ jù lọ ní ilẹ̀ Rọ́ṣíà.
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Àwọn Tó Máa Ń Fi Ọ̀ranyàn Báni Tage? 9
Báwo ni Kristẹni ọ̀dọ́ kan ṣe lè kojú ìwà tí ń yọni lẹ́nu yìí? Ǹjẹ́ ọ̀nà kan wà tí a lè gbà dènà rẹ̀?
[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 2]
Àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì ń ṣèwádìí nípa àwọn ohun tíntìntín tí wọ́n kéré gan-an ju átọ́ọ̀mù lọ