ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sjj orin 37
  • Máa Sin Jèhófà Tọkàntọkàn

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Máa Sin Jèhófà Tọkàntọkàn
  • “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Fífi Gbogbo Ọkàn Sin Jèhófà
    Kọrin sí Jèhófà
  • Jèhófà Ni Ìyìn àti Ògo Yẹ!
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Jèhófà Mọyì Iṣẹ́ Ìsìn Rẹ Tí O Ṣe Tọkàntọkàn
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1997
  • Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ Èrè Látọ̀dọ̀ Jèhófà
    Kọrin sí Jèhófà
Àwọn Míì
“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
sjj orin 37

ORIN 37

Máa Sin Jèhófà Tọkàntọkàn

Bíi Ti Orí Ìwé

(Mátíù 22:37)

  1. 1. Jèhófà Ọba Aláṣẹ,

    Ìwọ ni mo fẹ́ máa gbọ́ràn sí.

    Mo nífẹ̀ẹ́ rẹ tọkàntọkàn.

    Ìwọ ni màá fi ayé mi sìn.

    Mo fẹ́ràn ìránnilétí rẹ,

    Mo sì ń pàwọn àṣẹ rẹ mọ́.

    (ÈGBÈ)

    Jèhófà, mo nífẹ̀ẹ́ rẹ gan-an.

    Màá fi gbogbo ọkàn mi sìn ọ́.

  2. 2. Gbogbo iṣẹ́ rẹ ń gbé ọ ga;

    Láyé lọ́run, wọ́n ń fògo rẹ hàn.

    Èmi náà fẹ́ máa fokun mi

    Kéde orúkọ rẹ fáráyé.

    Màá fi gbogbo ayé mi sìn ọ́,

    Màá sì jẹ́ olóòótọ́ sí ọ.

    (ÈGBÈ)

    Jèhófà, mo nífẹ̀ẹ́ rẹ gan-an.

    Màá fi gbogbo ọkàn mi sìn ọ́.

(Tún wo Diu. 6:15; Sm. 40:8; 113:​1-3; Oníw. 5:4; Jòh. 4:34.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́