ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 January ojú ìwé 1
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
  • ○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́
  • ○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ
  • Bá A Ṣe Lè Lo Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Bá A Ṣe Lè Lo Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 January ojú ìwé 1
Àwọn akéde ń fi ìwé àṣàrò kúkúrú lọni nítòsí ìlú Monrovia, lórílẹ̀-èdè Làìbéríà

Àwọn akéde ń wàásù nítòsí ìlú Monrovia, lórílẹ̀-èdè Liberia

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Ṣé o rò pé Bíbélì ṣì wúlò fún wa lóde òní?

Bíbélì: 2Ti 3:16

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ni Bíbélì dá lé?

○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Kí ni Bíbélì dá lé?

Bíbélì: Mt 6:10

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ni Ìjọba Ọlọ́run máa ṣe?

○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ

Ìbéèrè: Kí ni Ìjọba Ọlọ́run máa ṣe?

Bíbélì: Da 2:44

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni ayé ṣe máa wá rí?

Bẹ̀rẹ̀ láti oṣù yìí lọ, kò ní sí ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ apá mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tá a máa ń ṣe ní ìpàdé àárín ọ̀sẹ̀ mọ́. Dípò ìyẹn, Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ máa ní apá kan tá a pè ní ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lábẹ́ rẹ̀, a máa rí ìbéèrè kan tá a lè fi bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò, ẹsẹ Bíbélì tá a máa kà, àti ìbéèrè fún ìgbà míì. Ní ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀, fídíò kan la ó máa wò ní apá “Máa Lo Ara Rẹ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù.” Akéde kọ̀ọ̀kan ló máa pinnu ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tàbí fídíò tó máa lò àti ìgbà tó máa lò ó, bóyá nígbà àkọ́kọ́ tàbí nígba ìpadàbẹ̀wò. Ní àfikún sí èyí, a máa rí àbá méjì nínú ìwé ìpàdé wa tó máa sọ bá a ṣe lè máa bá ìjíròrò tá a ti bẹ̀rẹ̀ nìṣó. Ọ̀nà tuntun yìí máa jẹ́ ká lè túbọ̀ máa kọ́ “gbogbo àwọn tí wọ́n ní ìtẹ̀sí-ọkàn títọ́ fún ìyè àìnípẹ̀kun.”​—Iṣe 13:48.

Iṣẹ́ Ọmọ Ilé Ẹ̀kọ́: Kí àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ ṣe àṣefihàn àwọn ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ, àfi tí ìtọ́ni bá sọ pé kí wọ́n má ṣe bẹ́ẹ̀.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́