Nóà àti ìdílé rẹ̀ ń múra láti wọnú ọkọ̀ áàkì
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Kí ni orúkọ Ọlọ́run?
Bíbélì: Sm 83:18
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ànímọ́ Jèhófà wo ló ta yọ jù lọ?
○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Ànímọ́ Jèhófà wo ló ta yọ jù lọ?
Bíbélì: 1Jo 4:8
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí la lè ṣe tá a bá fẹ́ di ọ̀rẹ́ Ọlọ́run?
○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ
Ìbéèrè: Kí la lè ṣe tá a bá fẹ́ di ọ̀rẹ́ Ọlọ́run?
Bíbélì: Jo 17:3
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ṣé Ọlọ́run ti sọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú fún wa?