January 6-12
JẸ́NẸ́SÍSÌ 1-2
Orin 11 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jèhófà Dá Àwọn Nǹkan Sórí Ilẹ̀ Ayé”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jẹ́nẹ́sísì.]
Jẹ 1:3, 4, 6, 9, 11—Ọjọ́ kìíní ìṣẹ̀dá sí ọjọ́ kẹta (it-1 527-528)
Jẹ 1:14, 20, 24, 27—Ọjọ́ kẹrin ìṣẹ̀dá sí ọjọ́ kẹfà (it-1 528 ¶5-8)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 1:1-19 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Sọ Bí Ọ̀rọ̀ Rẹ Ṣe Wúlò, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 13 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni.
Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w08 2/1 5—Àkòrí: Ọkàn Wa Balẹ̀ Bá A Ṣe Mọ̀ Pé Ọlọ́run Ló Dá Wa. (th ẹ̀kọ́ 11)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ǹjẹ́ O Lè Ṣàlàyé Ohun Tó O Gbà Gbọ́?”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo àwọn fídíò náà, Dókítà Tó Ń To Egungun Ṣàlàyé Ohun Tó Gbà Gbọ́ àti Onímọ̀ Nípa Ẹranko Kan Sọ Ìdí Tó Fi Gbà Ọlọ́run Gbọ́.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 14 ¶14-19
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Orin 18 àti Àdúrà