ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 1-2 Jèhófà Dá Àwọn Nǹkan Sórí Ilẹ̀ Ayé 1:3, 4, 6, 9, 11, 14, 20, 24, 27 Kọ àwọn ohun tí Jèhófà ṣe ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kan ìṣẹ̀dá. Ọjọ́ Kìíní Ọjọ́ Kejì Ọjọ́ Kẹta Ọjọ́ Kẹrin Ọjọ́ Karùn-ún Ọjọ́ Kẹfà