ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jẹ́nẹ́sísì

      • Ọlọ́run dá ọ̀run àti ayé (1, 2)

      • Àwọn ohun tí Ọlọ́run dá ní ọjọ́ kìíní sí ìkẹfà (3-31)

        • Ọjọ́ 1: ìmọ́lẹ̀; ọ̀sán àti òru (3-5)

        • Ọjọ́ 2: òfúrufú (6-8)

        • Ọjọ́ 3: ilẹ̀ àti ewéko (9-13)

        • Ọjọ́ 4: àwọn orísun ìmọ́lẹ̀ tó wà lọ́run (14-19)

        • Ọjọ́ 5: àwọn ẹja àtàwọn ẹyẹ (20-23)

        • Ọjọ́ 6: àwọn ẹran orí ilẹ̀ àti èèyàn (24-31)

Jẹ́nẹ́sísì 1:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 102:25; Ais 42:5; 45:18; Ro 1:20; Heb 1:10; Ifi 4:11; 10:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àlàyé Àwọn Ẹsẹ Bíbélì, àpilẹ̀kọ 2

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 6

    Jí!,

    No. 3 2021 ojú ìwé 10

    10/2006, ojú ìwé 29

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 1 2019 ojú ìwé 5

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2015, ojú ìwé 5

    2/15/2011, ojú ìwé 6-7

    2/15/2007, ojú ìwé 5-6

    2/1/1992, ojú ìwé 8-9

    Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?, ojú ìwé 4

    Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run, ojú ìwé 7

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 31

Jẹ́nẹ́sísì 1:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “omi tó ń ru gùdù.”

  • *

    Tàbí “agbára ìṣiṣẹ́ Ọlọ́run.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 8:27, 28
  • +Sm 33:6; Ais 40:26
  • +Sm 104:5, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 6

    Jí!,

    No. 3 2021 ojú ìwé 10

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2007, ojú ìwé 5-6

Jẹ́nẹ́sísì 1:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 45:7; 2Kọ 4:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 1/2020, ojú ìwé 1

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2011, ojú ìwé 8

    2/15/2007, ojú ìwé 6

    1/1/2004, ojú ìwé 28-29

Jẹ́nẹ́sísì 1:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 8:22

Jẹ́nẹ́sísì 1:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 1:20
  • +2Pe 3:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2008, ojú ìwé 27-28

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 72

Jẹ́nẹ́sísì 1:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 7:11; Owe 8:27, 28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 1/2020, ojú ìwé 1

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 72

Jẹ́nẹ́sísì 1:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 72

Jẹ́nẹ́sísì 1:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 38:8, 11; Sm 104:6-9; 136:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    No. 3 2021 ojú ìwé 10

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2007, ojú ìwé 6

Jẹ́nẹ́sísì 1:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 95:5
  • +Owe 8:29
  • +Di 32:4

Jẹ́nẹ́sísì 1:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 1/2020, ojú ìwé 1

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2007, ojú ìwé 6

Jẹ́nẹ́sísì 1:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 104:14

Jẹ́nẹ́sísì 1:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọn ìmọ́lẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 4:19
  • +Sm 104:19
  • +Jẹ 8:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2011, ojú ìwé 8

    2/15/2007, ojú ìwé 6

Jẹ́nẹ́sísì 1:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 136:7, 8
  • +Sm 8:3; Jer 31:35

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2007, ojú ìwé 6

    1/1/2004, ojú ìwé 28-29

Jẹ́nẹ́sísì 1:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 74:16

Jẹ́nẹ́sísì 1:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọn alààyè ọkàn.”

  • *

    Tàbí “òfúrufú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 2:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 1/2020, ojú ìwé 1

Jẹ́nẹ́sísì 1:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọn alààyè ọkàn.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 6

Jẹ́nẹ́sísì 1:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ne 9:6; Sm 104:25

Jẹ́nẹ́sísì 1:24

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọn alààyè ọkàn.”

  • *

    Tàbí “àwọn ẹran tó ń rìn káàkiri,” ó jọ pé àwọn ẹran afàyàfà àti oríṣiríṣi ẹran míì wà lára wọn.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 2:19

Jẹ́nẹ́sísì 1:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 6

Jẹ́nẹ́sísì 1:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 8:30; Jo 1:3; Kol 1:16
  • +1Kọ 11:7
  • +Jẹ 5:1; Jem 3:9
  • +Jẹ 9:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àlàyé Àwọn Ẹsẹ Bíbélì, àpilẹ̀kọ 27

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 6

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 2 2018 ojú ìwé 12

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2008, ojú ìwé 15

    1/1/2004, ojú ìwé 30

    2/15/2002, ojú ìwé 4

    11/15/2000, ojú ìwé 25

    1/15/1992, ojú ìwé 21

    2/1/1991, ojú ìwé 17

    Olùkọ́, ojú ìwé 22

    Mẹtalọkan, ojú ìwé 14

    “Sawo O!,” ojú ìwé 13-14

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 32-33

Jẹ́nẹ́sísì 1:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 139:14; Mt 19:4; Mk 10:6; 1Kọ 11:7, 9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 6

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 1 2019 ojú ìwé 10

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 2 2018 ojú ìwé 12

    Bíbélì Kọ́ Wa, ojú ìwé 53

    Bíbélì Fi Kọ́ni, ojú ìwé 48-49

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2013, ojú ìwé 3

    9/1/2012, ojú ìwé 4

    2/15/2011, ojú ìwé 9

    10/1/2008, ojú ìwé 15

    7/1/2005, ojú ìwé 4-5

    6/1/2002, ojú ìwé 9-10

    7/15/1997, ojú ìwé 4-5

    2/1/1997, ojú ìwé 9-10, 12

    6/15/1994, ojú ìwé 12

    4/1/1994, ojú ìwé 25

    Jí!,

    7/2013, ojú ìwé 13

    1/2010, ojú ìwé 26

    “Sawo O!,” ojú ìwé 13-14

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 42

Jẹ́nẹ́sísì 1:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 9:1
  • +Jẹ 2:15
  • +Sm 8:4, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2021, ojú ìwé 2

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 25

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 3 2019 ojú ìwé 6-7

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2018, ojú ìwé 19-20

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2016, ojú ìwé 9

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2006, ojú ìwé 4-5

    4/15/2004, ojú ìwé 4

    11/15/2000, ojú ìwé 25

    4/15/1999, ojú ìwé 8-9

    7/15/1998, ojú ìwé 15

    7/1/1991, ojú ìwé 9-10

    Jí!,

    10/8/1996, ojú ìwé 13-14

    “Sawo O!,” ojú ìwé 14-15

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 42-44

Jẹ́nẹ́sísì 1:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 9:3; Sm 104:14; Iṣe 14:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 44-45

Jẹ́nẹ́sísì 1:30

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ohun tó ní ẹ̀mí; ohun tó jẹ́ alààyè ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 147:9; Mt 6:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 44-45

Jẹ́nẹ́sísì 1:31

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:4; Sm 104:24; 1Ti 4:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 172

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2011, ojú ìwé 13

    1/1/2008, ojú ìwé 14-15

    11/15/1999, ojú ìwé 4-5

Àwọn míì

Jẹ́n. 1:1Sm 102:25; Ais 42:5; 45:18; Ro 1:20; Heb 1:10; Ifi 4:11; 10:6
Jẹ́n. 1:2Owe 8:27, 28
Jẹ́n. 1:2Sm 33:6; Ais 40:26
Jẹ́n. 1:2Sm 104:5, 6
Jẹ́n. 1:3Ais 45:7; 2Kọ 4:6
Jẹ́n. 1:5Jẹ 8:22
Jẹ́n. 1:6Jẹ 1:20
Jẹ́n. 1:62Pe 3:5
Jẹ́n. 1:7Jẹ 7:11; Owe 8:27, 28
Jẹ́n. 1:9Job 38:8, 11; Sm 104:6-9; 136:6
Jẹ́n. 1:10Sm 95:5
Jẹ́n. 1:10Owe 8:29
Jẹ́n. 1:10Di 32:4
Jẹ́n. 1:12Sm 104:14
Jẹ́n. 1:14Di 4:19
Jẹ́n. 1:14Sm 104:19
Jẹ́n. 1:14Jẹ 8:22
Jẹ́n. 1:16Sm 136:7, 8
Jẹ́n. 1:16Sm 8:3; Jer 31:35
Jẹ́n. 1:18Sm 74:16
Jẹ́n. 1:20Jẹ 2:19
Jẹ́n. 1:22Ne 9:6; Sm 104:25
Jẹ́n. 1:24Jẹ 2:19
Jẹ́n. 1:26Owe 8:30; Jo 1:3; Kol 1:16
Jẹ́n. 1:261Kọ 11:7
Jẹ́n. 1:26Jẹ 5:1; Jem 3:9
Jẹ́n. 1:26Jẹ 9:2
Jẹ́n. 1:27Sm 139:14; Mt 19:4; Mk 10:6; 1Kọ 11:7, 9
Jẹ́n. 1:28Jẹ 9:1
Jẹ́n. 1:28Jẹ 2:15
Jẹ́n. 1:28Sm 8:4, 6
Jẹ́n. 1:29Jẹ 9:3; Sm 104:14; Iṣe 14:17
Jẹ́n. 1:30Sm 147:9; Mt 6:26
Jẹ́n. 1:31Di 32:4; Sm 104:24; 1Ti 4:4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jẹ́nẹ́sísì 1:1-31

Jẹ́nẹ́sísì

1 Ní ìbẹ̀rẹ̀, Ọlọ́run dá ọ̀run àti ayé.+

2 Nígbà yẹn, ayé wà ní bọrọgidi, ó sì ṣófo. Òkùnkùn bo ibú omi,*+ ẹ̀mí Ọlọ́run*+ sì ń lọ káàkiri lójú omi.+

3 Ọlọ́run wá sọ pé: “Kí ìmọ́lẹ̀ wà.” Ìmọ́lẹ̀ sì wà.+ 4 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run rí i pé ìmọ́lẹ̀ náà dára, Ọlọ́run sì bẹ̀rẹ̀ sí í pààlà sáàárín ìmọ́lẹ̀ àti òkùnkùn. 5 Ọlọ́run pe ìmọ́lẹ̀ ní Ọ̀sán, ó sì pe òkùnkùn ní Òru.+ Ilẹ̀ ṣú, ilẹ̀ sì mọ́, èyí ni ọjọ́ kìíní.

6 Ọlọ́run sì sọ pé: “Kí òfúrufú+ wà láàárín omi, kí omi sì pín sọ́tọ̀ọ̀tọ̀.”+ 7 Ọlọ́run wá ṣe òfúrufú, ó pààlà sáàárín omi tó wà lókè òfúrufú náà àti omi tó wà ní ìsàlẹ̀ rẹ̀.+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀. 8 Ọlọ́run pe òfúrufú ní Ọ̀run. Ilẹ̀ ṣú, ilẹ̀ sì mọ́, èyí ni ọjọ́ kejì.

9 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ pé: “Kí àwọn omi tó wà lábẹ́ ọ̀run wọ́ jọ síbì kan, kí ilẹ̀ sì fara hàn.”+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀. 10 Ọlọ́run pe ilẹ̀ náà ní Ayé,+ àmọ́ ó pe omi tó wọ́ jọ ní Òkun.+ Ọlọ́run sì rí i pé ó dára.+ 11 Ọlọ́run sì sọ pé: “Kí koríko hù ní ayé, pẹ̀lú àwọn ewéko tó ní irúgbìn àti àwọn igi eléso tó ní irúgbìn ní irú tiwọn.” Ó sì rí bẹ́ẹ̀. 12 Koríko bẹ̀rẹ̀ sí í hù ní ayé pẹ̀lú àwọn ewéko tó ní irúgbìn+ àti àwọn igi eléso tó ní irúgbìn ní irú tiwọn. Ọlọ́run sì rí i pé ó dára. 13 Ilẹ̀ ṣú, ilẹ̀ sì mọ́, èyí ni ọjọ́ kẹta.

14 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ pé: “Kí orísun ìmọ́lẹ̀*+ wà ní ojú ọ̀run, kí ìyàtọ̀ lè wà láàárín ọ̀sán àti òru,+ wọ́n á sì jẹ́ àmì láti fi mọ àwọn àsìkò, ọjọ́ àti ọdún.+ 15 Wọ́n á jẹ́ orísun ìmọ́lẹ̀ tí á máa tàn sórí ayé láti ojú ọ̀run.” Ó sì rí bẹ́ẹ̀. 16 Ọlọ́run ṣe orísun ìmọ́lẹ̀ ńlá méjì, èyí tó tóbi á máa yọ ní ọ̀sán,+ èyí tó kéré á sì máa yọ ní òru, ó sì dá àwọn ìràwọ̀.+ 17 Ọlọ́run wá fi wọ́n sí ojú ọ̀run kí wọ́n lè máa tàn sórí ayé, 18 kí wọ́n lè máa yọ ní ọ̀sán àti ní òru, kí wọ́n sì mú kí ìyàtọ̀ wà láàárín ìmọ́lẹ̀ àti òkùnkùn.+ Ọlọ́run sì rí i pé ó dára. 19 Ilẹ̀ ṣú, ilẹ̀ sì mọ́, èyí ni ọjọ́ kẹrin.

20 Ọlọ́run sì sọ pé: “Kí àwọn ohun alààyè* máa gbá yìn-ìn nínú omi, kí àwọn ẹ̀dá tó ń fò sì máa fò lójú ọ̀run.”*+ 21 Ọlọ́run sì dá àwọn ẹran ńlá inú òkun àti gbogbo ohun alààyè* tó ń gbá yìn-ìn nínú omi ní irú tiwọn àti àwọn ẹ̀dá abìyẹ́ ní irú tiwọn. Ọlọ́run sì rí i pé ó dára. 22 Torí náà, Ọlọ́run súre fún wọn pé: “Ẹ máa bímọ, kí ẹ sì pọ̀, kí ẹ kún inú omi òkun,+ kí àwọn ẹ̀dá tó ń fò sì pọ̀ ní ayé.” 23 Ilẹ̀ ṣú, ilẹ̀ sì mọ́, èyí ni ọjọ́ karùn-ún.

24 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run wá sọ pé: “Kí ilẹ̀ mú àwọn ohun alààyè* jáde ní irú tiwọn, àwọn ẹran ọ̀sìn, àwọn ẹran tó ń rákò* àti àwọn ẹran inú igbó ní irú tiwọn.”+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀. 25 Ọlọ́run dá àwọn ẹran inú igbó ní irú tiwọn àti àwọn ẹran ọ̀sìn ní irú tiwọn àti àwọn ẹran tó ń rákò ní irú tiwọn. Ọlọ́run sì rí i pé ó dára.

26 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ pé: “Jẹ́ ká+ dá èèyàn ní àwòrán wa,+ kí wọ́n jọ wá,+ kí wọ́n sì máa jọba lórí àwọn ẹja inú òkun, àwọn ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run, àwọn ẹran ọ̀sìn, lórí gbogbo ayé àti lórí gbogbo ẹran tó ń rákò tó sì ń rìn lórí ilẹ̀.”+ 27 Ọlọ́run sì dá èèyàn ní àwòrán rẹ̀, ó dá a ní àwòrán Ọlọ́run; akọ àti abo ló dá wọn.+ 28 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run súre fún wọn, Ọlọ́run sọ fún wọn pé: “Ẹ máa bímọ, kí ẹ sì pọ̀, kí ẹ kún ayé,+ kí ẹ sì ṣèkáwọ́ rẹ̀,+ kí ẹ máa jọba lórí+ àwọn ẹja inú òkun, àwọn ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run àti lórí gbogbo ohun alààyè tó ń rìn lórí ilẹ̀.”

29 Ọlọ́run sì sọ pé: “Mo fún yín ní gbogbo ewéko ní gbogbo ayé, àwọn tó ní irúgbìn àti gbogbo igi eléso tó ní irúgbìn. Kí wọ́n jẹ́ oúnjẹ fún yín.+ 30 Mo sì fi gbogbo ewéko tútù ṣe oúnjẹ fún gbogbo ẹran inú igbó àti gbogbo ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run àti gbogbo ohun abẹ̀mí* tó ń rìn lórí ilẹ̀.”+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀.

31 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run rí gbogbo ohun tó ti ṣe, sì wò ó! ó dára gan-an.+ Ilẹ̀ ṣú, ilẹ̀ sì mọ́, èyí ni ọjọ́ kẹfà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́