ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • wp22 No. 1 ojú ìwé 16
  • Ibi Gbogbo Ni Ìkórìíra Wà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ibi Gbogbo Ni Ìkórìíra Wà
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • A Lè Borí Ìkórìíra!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2022
  • Kí Nìdí Tí Ìkórìíra Fi Pọ̀ Láyé?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2022
  • Ìkórìíra Èé Ṣe Tí Ó Fi Pọ̀ Tó Bẹ́ẹ̀?
    Jí!—1997
  • Ìkórìíra Yóò Ha Dópin Láé Bí?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1995
Àwọn Míì
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2022
wp22 No. 1 ojú ìwé 16
Ọkùnrin tó ni ilé ìtajà kan ń wo ìta látojú wíńdò lẹ́yìn táwọn jàǹdùkú fọ́ ilé ìtajà náà, àwọn òṣìṣẹ́ ilé ìtajà náà sì ń kó èérún gíláàsì tó fọ́.

Ibi Gbogbo Ni Ìkórìíra Wà

Kò síbi kan láyé yìí táwọn èèyàn ò ti lẹ́mìí ìkórìíra.

Léraléra làwọn oníròyìn ń sọ̀rọ̀ nípa báwọn èèyàn ṣe kórìíra ara wọn. Oríṣiríṣi ọ̀nà làwọn èèyàn ń gbà fẹ̀mí ìkórìíra hàn, wọ́n ń ṣe bẹ́ẹ̀ lójúkojú, lórí ìkànnì àjọlò, lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì tàbí kí wọ́n kọ lẹ́tà. Yàtọ̀ síyẹn, wọ́n ti halẹ̀ mọ́ àwọn kan, wọ́n kan àwọn míì lábùkù, wọ́n lé àwọn kan kúrò nílùú, wọ́n sì ba ohun ìní àwọn míì jẹ́. Kò síbi téèyàn yíjú sí tí ò ti ní ráwọn èèyàn tó ń jìyà nítorí ìkórìíra. Ó délé ó dóko!

Ìwé yìí á jẹ́ kó o mọ bó o ṣe lè borí ìkórìíra. Jẹ́ kó dá ẹ lójú pé o lè borí, kì í ṣe ohun tí kò ṣeé ṣe, kódà ọ̀pọ̀ èèyàn ló ti borí ìkórìíra kárí ayé.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́