ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 21:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Kí o sọ ọ́ di mímọ́,+ torí òun ló ń gbé oúnjẹ Ọlọ́run rẹ wá. Kó jẹ́ mímọ́ sí ọ, torí èmi Jèhófà, tó ń sọ yín di mímọ́, jẹ́ mímọ́.+

  • Nọ́ńbà 16:5-7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Ó sì sọ fún Kórà àti gbogbo àwọn tó ń tì í lẹ́yìn pé: “Tó bá di àárọ̀, Jèhófà máa jẹ́ ká mọ ẹni tó jẹ́ tirẹ̀+ àti ẹni tó jẹ́ mímọ́ àti ẹni tó gbọ́dọ̀ máa sún mọ́ ọn,+ ẹnikẹ́ni tó bá sì yàn+ ló máa sún mọ́ ọn. 6 Ohun tí ẹ máa ṣe nìyí: Kí ìwọ Kórà àti gbogbo àwọn tó ń tì ọ́ lẹ́yìn+ mú ìkóná,+ 7 kí ẹ fi iná sí i, kí ẹ sì fi tùràrí sí i níwájú Jèhófà lọ́la, ẹni tí Jèhófà bá sì yàn,+ òun ni ẹni mímọ́. “Ó tó gẹ́ẹ́, ẹ̀yin ọmọ Léfì!”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́