ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 2:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ó ń gbé aláìní dìde látinú eruku;

      Ó ń gbé tálákà dìde látinú eérú,*+

      Láti mú kí wọ́n jókòó pẹ̀lú àwọn olórí,

      Ó fún wọn ní ìjókòó iyì.

      Ti Jèhófà ni àwọn ìpìlẹ̀ ayé,+

      Ó sì gbé ilẹ̀ tó ń mú èso jáde ka orí wọn.

  • Sáàmù 113:6-8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Ó tẹ̀ ba láti wo ọ̀run àti ayé,+

       7 Ó ń gbé aláìní dìde látinú eruku.

      Ó ń gbé tálákà dìde látorí eérú*+

       8 Kí ó lè mú un jókòó pẹ̀lú àwọn èèyàn pàtàkì,

      Àwọn ẹni pàtàkì nínú àwọn èèyàn rẹ̀.

  • Àìsáyà 57:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Torí ohun tí Ẹni Gíga àti Ẹni Tó Ta Yọ sọ nìyí,

      Tó wà láàyè* títí láé,+ tí orúkọ rẹ̀ sì jẹ́ mímọ́:+

      “Ibi gíga àti ibi mímọ́ ni mò ń gbé,+

      Àmọ́ mo tún ń gbé pẹ̀lú àwọn tí a tẹ̀ rẹ́, tí wọ́n sì rẹ̀wẹ̀sì ní ẹ̀mí,

      Láti mú kí ẹ̀mí ẹni tó rẹlẹ̀ sọ jí,

      Kí n sì mú kí ọkàn àwọn tí a tẹ̀ rẹ́ sọ jí.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́