ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 59:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 59 Ọlọ́run mi, gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi;+

      Dáàbò bò mí lọ́wọ́ àwọn tó ń dìde sí mi.+

  • Sáàmù 61:3, 4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Nítorí ìwọ ni ibi ààbò mi,

      Ilé gogoro alágbára tó ń dáàbò bò mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá.+

       4 Màá wà* nínú àgọ́ rẹ títí láé;+

      Màá fi abẹ́ ìyẹ́ apá rẹ ṣe ibi ààbò.+ (Sélà)

  • Sáàmù 91:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 91 Ẹni tó bá ń gbé ibi ìkọ̀kọ̀ Ẹni Gíga Jù Lọ+

      Yóò máa gbé lábẹ́ òjìji Olódùmarè.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́