ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 137:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ìwọ ọmọbìnrin Bábílónì, tí kò ní pẹ́ di ahoro,+

      Aláyọ̀ ni ẹni tó máa san ọ́ lẹ́san

      Lórí ohun tí o ṣe sí wa.+

  • Jeremáyà 50:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 “Ẹ kó àwọn tafàtafà jọ láti gbéjà ko Bábílónì,

      Gbogbo àwọn tó ń tẹ* ọrun.+

      Ẹ pàgọ́ yí i ká; kí ẹnikẹ́ni má ṣe sá àsálà.

      Ẹ san án fún un gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.+

      Bí ó ti ṣe sí àwọn èèyàn ni kí ẹ ṣe sí i gẹ́lẹ́.+

      Nítorí pé ó ti gbéra ga sí Jèhófà,

      Sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì.+

  • Jeremáyà 51:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Ẹ sá kúrò nínú Bábílónì,

      Kí ẹ sì sá nítorí ẹ̀mí* yín.+

      Ẹ má ṣègbé nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.

      Nítorí àkókò ẹ̀san Jèhófà ti tó.

      Ó máa san ohun tó ṣe pa dà fún un.+

  • Jeremáyà 51:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Màá san án pa dà fun Bábílónì àti fún gbogbo àwọn tó ń gbé ní Kálídíà

      Nítorí gbogbo búburú tí wọ́n ti ṣe ní Síónì lójú yín,”+ ni Jèhófà wí.

  • Ìfihàn 18:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Bó ṣe ṣe sí àwọn míì ni kí ẹ ṣe sí i,+ àní ìlọ́po méjì ohun tó ṣe ni kí ẹ san fún un;+ nínú ife+ tó fi po àdàlù, kí ẹ po ìlọ́po méjì àdàlù náà fún un.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́