ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 2:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Ẹ jẹ́ kí n kéde àṣẹ Jèhófà;

      Ó sọ fún mi pé: “Ìwọ ni ọmọ mi;+

      Òní ni mo di bàbá rẹ.+

  • Àìsáyà 42:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 42 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi,+ tí mò ń tì lẹ́yìn!

      Àyànfẹ́ mi,+ ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+

      Mo ti fi ẹ̀mí mi sínú rẹ̀;+

      Ó máa mú ìdájọ́ òdodo wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+

  • Mátíù 3:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Wò ó! Ohùn kan tún dún láti ọ̀run+ pé: “Èyí ni Ọmọ mi,+ àyànfẹ́, ẹni tí mo ti tẹ́wọ́ gbà.”+

  • 2 Pétérù 1:17, 18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Torí ó gba ọlá àti ògo láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run tó jẹ́ Baba, nígbà tí ògo ọlá ńlá sọ irú ọ̀rọ̀ yìí fún un* pé: “Èyí ni Ọmọ mi, àyànfẹ́ mi, ẹni tí èmi fúnra mi tẹ́wọ́ gbà.”+ 18 Àní, ọ̀rọ̀ yìí la gbọ́ láti ọ̀run nígbà tí a wà pẹ̀lú rẹ̀ ní òkè mímọ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́