ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 14
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Diutarónómì

      • Ohun tí kò yẹ kí wọ́n ṣe nítorí òkú (1, 2)

      • Àwọn oúnjẹ tó mọ́ àti èyí tí kò mọ́ (3-21)

      • Kí wọ́n mú ìdá mẹ́wàá wá fún Jèhófà (22-29)

Diutarónómì 14:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “mú kí àárín ojú yín pá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 19:28
  • +Le 21:1, 5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 1/2021,

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2004, ojú ìwé 27

Diutarónómì 14:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tó ṣeyebíye.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 19:2; 20:26; Di 28:9; 1Pe 1:15
  • +Ẹk 19:5, 6; Di 7:6

Diutarónómì 14:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 11:43; 20:25; Iṣe 10:14

Diutarónómì 14:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 11:2, 3

Diutarónómì 14:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ewúrẹ́ igbó.”

Diutarónómì 14:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 11:4-8

Diutarónómì 14:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 11:9, 10

Diutarónómì 14:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 11:13-20

Diutarónómì 14:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Gbogbo kòkòrò.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 1/2021,

Diutarónómì 14:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ẹnubodè.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 22:31; Le 17:15
  • +Ẹk 23:19; 34:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2005, ojú ìwé 27

    9/15/2004, ojú ìwé 26

Diutarónómì 14:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 12:11; 26:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 7/2021,

Diutarónómì 14:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 12:5, 17; 15:19, 20
  • +Sm 111:10

Diutarónómì 14:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 12:5, 6

Diutarónómì 14:26

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tí ọkàn rẹ bá fẹ́.”

  • *

    Tàbí “ohunkóhun tí ọkàn rẹ bá ń wá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 12:7; 26:11; Sm 100:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2010, ojú ìwé 23

Diutarónómì 14:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 18:21; 2Kr 31:4; 1Kọ 9:13
  • +Nọ 18:20; Di 10:9

Diutarónómì 14:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 26:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 7/2021,

Diutarónómì 14:29

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aláìlóbìí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 22:21; Di 10:18; Jem 1:27
  • +Di 15:10; Sm 41:1; Owe 11:24; 19:17; Mal 3:10; Lk 6:35

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 7/2021,

Àwọn míì

Diu. 14:1Le 19:28
Diu. 14:1Le 21:1, 5
Diu. 14:2Le 19:2; 20:26; Di 28:9; 1Pe 1:15
Diu. 14:2Ẹk 19:5, 6; Di 7:6
Diu. 14:3Le 11:43; 20:25; Iṣe 10:14
Diu. 14:4Le 11:2, 3
Diu. 14:7Le 11:4-8
Diu. 14:9Le 11:9, 10
Diu. 14:12Le 11:13-20
Diu. 14:21Ẹk 22:31; Le 17:15
Diu. 14:21Ẹk 23:19; 34:26
Diu. 14:22Di 12:11; 26:12
Diu. 14:23Di 12:5, 17; 15:19, 20
Diu. 14:23Sm 111:10
Diu. 14:24Di 12:5, 6
Diu. 14:26Di 12:7; 26:11; Sm 100:2
Diu. 14:27Nọ 18:21; 2Kr 31:4; 1Kọ 9:13
Diu. 14:27Nọ 18:20; Di 10:9
Diu. 14:28Di 26:12
Diu. 14:29Ẹk 22:21; Di 10:18; Jem 1:27
Diu. 14:29Di 15:10; Sm 41:1; Owe 11:24; 19:17; Mal 3:10; Lk 6:35
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Diutarónómì 14:1-29

Diutarónómì

14 “Ọmọ Jèhófà Ọlọ́run yín lẹ jẹ́. Ẹ ò gbọ́dọ̀ kọ ara yín ní abẹ+ tàbí kí ẹ fá iwájú orí yín* torí òkú.+ 2 Torí èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́+ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, Jèhófà sì ti yàn yín kí ẹ lè di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,* nínú gbogbo èèyàn tó wà láyé.+

3 “O ò gbọ́dọ̀ jẹ ohunkóhun tó ń ríni lára.+ 4 Àwọn ẹran tí ẹ lè jẹ nìyí:+ akọ màlúù, àgùntàn, ewúrẹ́, 5 àgbọ̀nrín, egbin, èsúwó, ẹ̀kìrì,* ẹtu, àgùntàn igbó àti àgùntàn orí àpáta. 6 Ẹ lè jẹ ẹran èyíkéyìí tí pátákò rẹ̀ là sí méjì, tó sì ń jẹ àpọ̀jẹ. 7 Àmọ́, ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ àwọn ẹran yìí tí wọ́n ń jẹ àpọ̀jẹ tàbí tí pátákò wọn là nìkan: ràkúnmí, ehoro àti gara orí àpáta, torí pé wọ́n ń jẹ àpọ̀jẹ ṣùgbọ́n pátákò wọn ò là. Aláìmọ́ ni wọ́n jẹ́ fún yín.+ 8 Bákan náà ni ẹlẹ́dẹ̀, torí pátákò rẹ̀ là, àmọ́ kì í jẹ àpọ̀jẹ. Aláìmọ́ ló jẹ́ fún yín. Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹran wọn, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ fọwọ́ kan òkú wọn.

9 “Nínú gbogbo ohun tó ń gbé inú omi, èyí tí ẹ lè jẹ nìyí: Ẹ lè jẹ ohunkóhun tó bá ní lẹ́bẹ́ àti ìpẹ́.+ 10 Àmọ́ ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ohunkóhun tí kò bá ní lẹ́bẹ́ àti ìpẹ́. Aláìmọ́ ló jẹ́ fún yín.

11 “Ẹ lè jẹ ẹyẹ èyíkéyìí tó bá mọ́. 12 Àmọ́ ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ àwọn ẹyẹ yìí: idì, idì ajẹja, igún dúdú,+ 13 àwòdì pupa, àwòdì dúdú, onírúurú ẹyẹ aṣọdẹ, 14 gbogbo onírúurú ẹyẹ ìwò, 15 ògòǹgò, òwìwí, ẹyẹ àkẹ̀, onírúurú àṣáǹwéwé, 16 òwìwí kékeré, òwìwí elétí gígùn, ògbùgbú, 17 ẹyẹ òfú, igún, ẹyẹ àgò, 18 ẹyẹ àkọ̀, onírúurú ẹyẹ wádòwádò, àgbìgbò àti àdán. 19 Gbogbo ẹ̀dá abìyẹ́ tó ń gbá yìn-ìn* pẹ̀lú jẹ́ aláìmọ́ fún yín. Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ wọ́n. 20 Ẹ lè jẹ ẹ̀dá èyíkéyìí tó ń fò, tó sì mọ́.

21 “Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ òkú ẹran èyíkéyìí.+ Ẹ lè fún àjèjì tó wà nínú àwọn ìlú* yín, kó sì jẹ ẹ́ tàbí kí ẹ tà á fún àjèjì. Torí pé èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run yín.

“Ẹ ò gbọ́dọ̀ se ọmọ ewúrẹ́ nínú wàrà ìyá rẹ̀.+

22 “O gbọ́dọ̀ rí i pé ò ń san ìdá mẹ́wàá gbogbo ohun tí irúgbìn rẹ bá ń mú jáde lọ́dọọdún.+ 23 Iwájú Jèhófà Ọlọ́run rẹ ni kí o ti máa jẹ ìdá mẹ́wàá ọkà rẹ, wáìnì tuntun rẹ, òróró rẹ àti àwọn àkọ́bí nínú ọ̀wọ́ ẹran àti agbo ẹran rẹ, ní ibi tó yàn pé kí orúkọ rẹ̀ máa wà,+ kí o lè kọ́ láti máa bẹ̀rù Jèhófà Ọlọ́run rẹ nígbà gbogbo.+

24 “Àmọ́ tí ọ̀nà ibẹ̀ bá jìn jù fún ọ, tó ò sì lè gbé e lọ sí ibi tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ yàn pé kí orúkọ rẹ̀ máa wà+ torí pé ibẹ̀ jìnnà sí ọ, (torí pé Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa bù kún ọ,) 25 o lè sọ ọ́ di owó, kí o wá mú owó náà dání, kí o sì rìnrìn àjò lọ sí ibi tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa yàn. 26 O lè wá fi owó náà ra ohunkóhun tó bá wù ọ́,* bíi màlúù, àgùntàn, ewúrẹ́, wáìnì àtàwọn ohun mímu míì tó ní ọtí àti ohunkóhun tí o bá fẹ́;* kí o jẹ ẹ́ níbẹ̀ níwájú Jèhófà Ọlọ́run rẹ, kí o sì máa yọ̀, ìwọ àti agbo ilé rẹ.+ 27 O ò gbọ́dọ̀ gbàgbé ọmọ Léfì tó wà nínú àwọn ìlú rẹ,+ torí wọn ò fún un ní ìpín tàbí ogún kankan pẹ̀lú rẹ.+

28 “Ní òpin ọdún mẹ́ta-mẹ́ta, kí o kó gbogbo ìdá mẹ́wàá èso rẹ ní ọdún yẹn jáde, kí o sì kó o sínú àwọn ìlú rẹ.+ 29 Ọmọ Léfì tí wọn ò fún ní ìpín tàbí ogún kankan pẹ̀lú rẹ, àjèjì, ọmọ aláìníbaba* àti opó tí wọ́n wà nínú àwọn ìlú rẹ máa wá, wọ́n á sì jẹun yó,+ kí Jèhófà Ọlọ́run rẹ lè máa bù kún ọ nínú gbogbo ohun tí ò ń ṣe.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́