ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kọ́ríńtì 7
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Kọ́ríńtì

      • Ìmọ̀ràn fún àwọn tí kò gbéyàwó àti àwọn tó ti gbéyàwó (1-16)

      • Ẹ wà ní ipò tí ẹ wà nígbà tí a pè yín (17-24)

      • Àwọn tí kò gbéyàwó àti àwọn opó (25-40)

        • Àǹfààní tó wà nínú kéèyàn wà láìgbéyàwó (32-35)

        • Gbéyàwó “kìkì nínú Olúwa” (39)

1 Kọ́ríńtì 7:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, ní ìbálòpọ̀ pẹ̀lú.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/15/1996, ojú ìwé 10-11

    Jí!,

    5/22/1996, ojú ìwé 7

1 Kọ́ríńtì 7:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó ń tọ́ka sí ọ̀rọ̀ Gíríìkì náà, por·neiʹa tí wọ́n bá lò ó fún ohun tó ju ẹyọ kan lọ. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 5:18, 19
  • +Jẹ 2:24; Heb 13:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ayọ̀ Ìdílé, ojú ìwé 156-157

1 Kọ́ríńtì 7:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 21:10; 1Kọ 7:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2011, ojú ìwé 17

    10/15/1996, ojú ìwé 16

    Ayọ̀ Ìdílé, ojú ìwé 157

1 Kọ́ríńtì 7:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/15/1996, ojú ìwé 16

1 Kọ́ríńtì 7:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2015, ojú ìwé 27

    10/15/2011, ojú ìwé 17

    10/15/1996, ojú ìwé 16

    Ayọ̀ Ìdílé, ojú ìwé 157-158

1 Kọ́ríńtì 7:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 19:10, 11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/15/1996, ojú ìwé 11

1 Kọ́ríńtì 7:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 7:39, 40; 9:5

1 Kọ́ríńtì 7:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Tẹ 4:4, 5; 1Ti 5:11, 14

1 Kọ́ríńtì 7:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 5:32; 19:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2018, ojú ìwé 13

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2000, ojú ìwé 28

1 Kọ́ríńtì 7:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mk 10:11; Lk 16:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2018, ojú ìwé 13

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2012, ojú ìwé 11

    12/15/2000, ojú ìwé 28

1 Kọ́ríńtì 7:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 7:25, 40

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/15/1996, ojú ìwé 21-22

1 Kọ́ríńtì 7:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2018, ojú ìwé 13-14

1 Kọ́ríńtì 7:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2016, ojú ìwé 16

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2006, ojú ìwé 26-28

1 Kọ́ríńtì 7:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “pínyà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 12:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2016, ojú ìwé 16-17

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2012, ojú ìwé 11-12

    12/15/2000, ojú ìwé 28

1 Kọ́ríńtì 7:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 3:1, 2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/1/1995, ojú ìwé 10-11

1 Kọ́ríńtì 7:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 7:7

1 Kọ́ríńtì 7:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kọlà.”

  • *

    Tàbí “aláìkọlà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 21:20
  • +Iṣe 10:45; 15:1, 24; Ga 5:2

1 Kọ́ríńtì 7:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ìkọlà.”

  • *

    Tàbí “àìkọlà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ga 6:15; Kol 3:11
  • +Onw 12:13; Jer 7:23; Ro 2:25; Ga 5:6; 1Jo 5:3

1 Kọ́ríńtì 7:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 7:17

1 Kọ́ríńtì 7:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ga 3:28

1 Kọ́ríńtì 7:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 8:36; Flm 15, 16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, ojú ìwé 1710

1 Kọ́ríńtì 7:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 6:19, 20; Heb 9:12; 1Pe 1:18, 19

1 Kọ́ríńtì 7:25

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọn tí kò tíì lọ́kọ tàbí láya.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 7:12, 40

1 Kọ́ríńtì 7:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/15/1996, ojú ìwé 11

1 Kọ́ríńtì 7:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mal 2:16; Mt 19:6; Ef 5:33

1 Kọ́ríńtì 7:28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2020, ojú ìwé 3

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2017, ojú ìwé 4-6

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2015, ojú ìwé 18-19

    10/15/2011, ojú ìwé 15-16

    4/15/2008, ojú ìwé 20

    5/1/2007, ojú ìwé 19

    9/15/2006, ojú ìwé 28-29

    2/15/1999, ojú ìwé 4

    10/15/1996, ojú ìwé 19

    6/15/1995, ojú ìwé 30

1 Kọ́ríńtì 7:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 13:11; 1Pe 4:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2016, ojú ìwé 17

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2008, ojú ìwé 27

    7/15/2000, ojú ìwé 30-31

    10/1/1999, ojú ìwé 9

    10/15/1996, ojú ìwé 19

    5/15/1992, ojú ìwé 19-20

    Yiyan, ojú ìwé 100

1 Kọ́ríńtì 7:30

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 100-102

1 Kọ́ríńtì 7:31

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “ìran.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2016, ojú ìwé 17

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2015, ojú ìwé 20

    11/15/2011, ojú ìwé 19

    11/15/2010, ojú ìwé 24

    1/15/2008, ojú ìwé 17-19

    10/1/2007, ojú ìwé 19

    2/1/2004, ojú ìwé 18-19

    2/1/2003, ojú ìwé 6

    10/15/1996, ojú ìwé 19

    Jí!,

    2/8/2001, ojú ìwé 11

    Yiyan, ojú ìwé 100-102

1 Kọ́ríńtì 7:32

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 42

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/15/1996, ojú ìwé 12-14

1 Kọ́ríńtì 7:33

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 5:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 42

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2008, ojú ìwé 27

    10/15/1996, ojú ìwé 16

1 Kọ́ríńtì 7:34

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 5:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2008, ojú ìwé 27

    10/15/1996, ojú ìwé 16-17

1 Kọ́ríńtì 7:35

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “dẹ okùn mú yín.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/15/1996, ojú ìwé 12-14

    6/15/1995, ojú ìwé 29-30

    5/15/1992, ojú ìwé 18

1 Kọ́ríńtì 7:36

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “hùwà tí kò yẹ sí ipò wúńdíá òun.”

  • *

    Ó ń tọ́ka sí ìgbà tí ìfẹ́ ìbálòpọ̀ máa ń lágbára lára ọ̀dọ́.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 19:12; 1Kọ 7:28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 42

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2000, ojú ìwé 31

    2/15/1999, ojú ìwé 5-6

    10/15/1996, ojú ìwé 14

    5/15/1992, ojú ìwé 14

    Ayọ̀ Ìdílé, ojú ìwé 15-16

1 Kọ́ríńtì 7:37

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “láti pa ipò wúńdíá rẹ̀ mọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 19:10, 11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2011, ojú ìwé 17

1 Kọ́ríńtì 7:38

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tó bá fi ipò wúńdíá rẹ̀ fúnni nínú ìgbéyàwó.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 7:32

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 42

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2012, ojú ìwé 20

    10/15/2011, ojú ìwé 17

    6/15/1995, ojú ìwé 29-30

    5/15/1992, ojú ìwé 18

1 Kọ́ríńtì 7:39

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 7:2
  • +Jẹ 24:2, 3; Di 7:3, 4; Ne 13:25, 26; 2Kọ 6:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 42

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2015, ojú ìwé 30-32

    1/15/2015, ojú ìwé 31-32

    10/15/2011, ojú ìwé 15

    3/15/2008, ojú ìwé 8

    7/1/2004, ojú ìwé 30-31

    8/15/2001, ojú ìwé 30

    5/15/2001, ojú ìwé 20-21

    Jí!,

    10/8/1999, ojú ìwé 21

    8/8/1999, ojú ìwé 26-28

    1/22/1998, ojú ìwé 20

1 Kọ́ríńtì 7:40

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/1997, ojú ìwé 6

Àwọn míì

1 Kọ́r. 7:2Owe 5:18, 19
1 Kọ́r. 7:2Jẹ 2:24; Heb 13:4
1 Kọ́r. 7:3Ẹk 21:10; 1Kọ 7:5
1 Kọ́r. 7:7Mt 19:10, 11
1 Kọ́r. 7:81Kọ 7:39, 40; 9:5
1 Kọ́r. 7:91Tẹ 4:4, 5; 1Ti 5:11, 14
1 Kọ́r. 7:10Mt 5:32; 19:6
1 Kọ́r. 7:11Mk 10:11; Lk 16:18
1 Kọ́r. 7:121Kọ 7:25, 40
1 Kọ́r. 7:15Heb 12:14
1 Kọ́r. 7:161Pe 3:1, 2
1 Kọ́r. 7:171Kọ 7:7
1 Kọ́r. 7:18Iṣe 21:20
1 Kọ́r. 7:18Iṣe 10:45; 15:1, 24; Ga 5:2
1 Kọ́r. 7:19Ga 6:15; Kol 3:11
1 Kọ́r. 7:19Onw 12:13; Jer 7:23; Ro 2:25; Ga 5:6; 1Jo 5:3
1 Kọ́r. 7:201Kọ 7:17
1 Kọ́r. 7:21Ga 3:28
1 Kọ́r. 7:22Jo 8:36; Flm 15, 16
1 Kọ́r. 7:231Kọ 6:19, 20; Heb 9:12; 1Pe 1:18, 19
1 Kọ́r. 7:251Kọ 7:12, 40
1 Kọ́r. 7:27Mal 2:16; Mt 19:6; Ef 5:33
1 Kọ́r. 7:29Ro 13:11; 1Pe 4:7
1 Kọ́r. 7:331Ti 5:8
1 Kọ́r. 7:341Ti 5:5
1 Kọ́r. 7:36Mt 19:12; 1Kọ 7:28
1 Kọ́r. 7:37Mt 19:10, 11
1 Kọ́r. 7:381Kọ 7:32
1 Kọ́r. 7:39Ro 7:2
1 Kọ́r. 7:39Jẹ 24:2, 3; Di 7:3, 4; Ne 13:25, 26; 2Kọ 6:14
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
  • 33
  • 34
  • 35
  • 36
  • 37
  • 38
  • 39
  • 40
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Kọ́ríńtì 7:1-40

Ìwé Kìíní sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì

7 Ní báyìí, ní ti àwọn ohun tí ẹ kọ̀wé nípa rẹ̀, ó sàn kí ọkùnrin má fọwọ́ kan* obìnrin; 2 àmọ́ nítorí ìṣekúṣe* tó gbòde kan, kí ọkùnrin kọ̀ọ̀kan ní aya tirẹ̀,+ kí obìnrin kọ̀ọ̀kan sì ní ọkọ tirẹ̀.+ 3 Kí ọkọ máa fún aya rẹ̀ ní ẹ̀tọ́ rẹ̀, kí aya sì máa ṣe bẹ́ẹ̀ fún ọkọ rẹ̀.+ 4 Aya kò láṣẹ lórí ara rẹ̀, ọkọ rẹ̀ ló láṣẹ; bákan náà, ọkọ kò láṣẹ lórí ara rẹ̀, aya rẹ̀ ló láṣẹ. 5 Ẹ má ṣe máa fi du ara yín àfi tó bá jẹ́ àjọgbà fún àkókò kan, kí ẹ lè ya àkókò sọ́tọ̀ fún àdúrà, kí ẹ sì pa dà wà pa pọ̀, kí Sátánì má bàa máa dẹ yín wò torí pé ẹ ò lè mára dúró. 6 Àmọ́, mi ò pa á láṣẹ o, mo kàn ń sọ ohun tí ẹ lè ṣe ni. 7 Ì bá wù mí kí gbogbo èèyàn dà bíi tèmi. Síbẹ̀, kálukú ló ní ẹ̀bùn tirẹ̀+ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run, ọ̀kan lọ́nà yìí, òmíràn lọ́nà yẹn.

8 Tóò, mo sọ fún àwọn tí kò gbéyàwó àti àwọn opó pé ó sàn kí wọ́n wà bí mo ṣe wà.+ 9 Àmọ́ tí wọn ò bá lè mára dúró, kí wọ́n gbéyàwó, torí ó sàn láti gbéyàwó ju kí ara ẹni máa gbóná nítorí ìfẹ́ ìbálòpọ̀.+

10 Mo fún àwọn tó ti ṣègbéyàwó ní ìtọ́sọ́nà, àmọ́ kì í ṣe èmi, Olúwa ni, pé kí aya má ṣe kúrò lọ́dọ̀ ọkọ rẹ̀.+ 11 Àmọ́ tó bá kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀, kí ó wà láìlọ́kọ, àìjẹ́ bẹ́ẹ̀ kó pa dà sọ́dọ̀ ọkọ rẹ̀; kí ọkọ má sì fi aya rẹ̀ sílẹ̀.+

12 Àmọ́ mo sọ fún àwọn yòókù, bẹ́ẹ̀ ni, èmi ni, kì í ṣe Olúwa+ pé: Tí arákùnrin èyíkéyìí bá ní aya tó jẹ́ aláìgbàgbọ́, tí obìnrin náà sì gbà láti máa bá a gbé, kí ó má fi obìnrin náà sílẹ̀; 13 tí obìnrin kan bá sì ní ọkọ tó jẹ́ aláìgbàgbọ́, tí ọkùnrin náà gbà láti máa bá a gbé, kí ó má fi ọkọ rẹ̀ sílẹ̀. 14 Nítorí ọkọ tó jẹ́ aláìgbàgbọ́ ni a sọ di mímọ́ nítorí aya rẹ̀, aya tó sì jẹ́ aláìgbàgbọ́ ni a sọ di mímọ́ nítorí arákùnrin náà; àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, àwọn ọmọ yín á jẹ́ aláìmọ́, àmọ́ ní báyìí wọ́n jẹ́ mímọ́. 15 Ṣùgbọ́n tí aláìgbàgbọ́ náà bá pinnu láti lọ,* jẹ́ kó máa lọ; irú ipò bẹ́ẹ̀ kò de arákùnrin kan tàbí arábìnrin kan, àmọ́ Ọlọ́run ti pè yín sí àlàáfíà.+ 16 Ìwọ aya, ṣé o mọ̀ bóyá wàá gba ọkọ rẹ là?+ Ìwọ ọkọ, ṣé o mọ̀ bóyá wàá gba aya rẹ là?

17 Síbẹ̀, gẹ́gẹ́ bí Jèhófà* ṣe fún kálukú ní ìpín tirẹ̀, kí kálukú máa rìn bí Ọlọ́run ṣe pè é.+ Torí náà, mo fi àṣẹ yìí lélẹ̀ nínú gbogbo ìjọ. 18 Ǹjẹ́ ọkùnrin kan wà tó ti dádọ̀dọ́* nígbà tí a pè é?+ Kí ó má pa dà di aláìdádọ̀dọ́.* Ǹjẹ́ ọkùnrin kan wà tó jẹ́ aláìdádọ̀dọ́ nígbà tí a pè é? Kí ó má ṣe dádọ̀dọ́.+ 19 Ìdádọ̀dọ́* kò túmọ̀ sí nǹkan kan, àìdádọ̀dọ́* kò sì túmọ̀ sí nǹkan kan;+ pípa àwọn àṣẹ Ọlọ́run mọ́ ni ohun tó ṣe pàtàkì.+ 20 Ipòkípò tí kálukú wà nígbà tí a pè é, kí ó wà bẹ́ẹ̀.+ 21 Ṣé ẹrú ni ọ́ nígbà tí a pè ọ́? Má ṣe jẹ́ kí ìyẹn dà ọ́ láàmú;+ àmọ́ tí o bá lè di òmìnira, tètè gbá àǹfààní náà mú. 22 Nítorí ẹnikẹ́ni tí a pè nínú Olúwa nígbà tó jẹ́ ẹrú ti di òmìnira nínú Olúwa; + bákan náà, ẹnikẹ́ni tí a pè nígbà tó wà ní òmìnira jẹ́ ẹrú Kristi. 23 A ti rà yín ní iye kan;+ ẹ má ṣe ẹrú èèyàn mọ́. 24 Ipòkípò tí kálukú wà nígbà tí a pè é, ẹ̀yin ará, kí ó wà bẹ́ẹ̀ níwájú Ọlọ́run.

25 Ní ti àwọn wúńdíá,* mi ò ní àṣẹ kankan látọ̀dọ̀ Olúwa, àmọ́ mo sọ èrò mi+ gẹ́gẹ́ bí ẹni tí Olúwa fi àánú hàn sí láti jẹ́ olóòótọ́. 26 Nítorí náà, mo rò pé ohun tó dáa jù lọ ni pé kí ọkùnrin kan wà bó ṣe wà nítorí ìṣòro ìsinsìnyí. 27 Ṣé o ti gbéyàwó? Má ṣe wá ọ̀nà láti fi í sílẹ̀.+ Ṣé o ò níyàwó mọ́? Má ṣe máa wá ìyàwó. 28 Àmọ́ tí o bá tiẹ̀ gbéyàwó, o ò dẹ́ṣẹ̀ kankan. Tí wúńdíá kan bá sì ṣègbéyàwó, irú ẹni bẹ́ẹ̀ kò dẹ́ṣẹ̀ kankan. Síbẹ̀, àwọn tó ṣe bẹ́ẹ̀ máa ní ìpọ́njú nínú ara wọn. Àmọ́ mi ò fẹ́ kí ẹ kó sínú ìṣòro.

29 Yàtọ̀ síyẹn, mo sọ èyí, ẹ̀yin ará, pé àkókò tó ṣẹ́ kù ti dín kù.+ Láti ìsinsìnyí lọ, kí àwọn tó níyàwó dà bíi pé wọn kò ní, 30 kí àwọn tó ń sunkún dà bí àwọn tí kò sunkún, kí àwọn tó ń yọ̀ dà bí àwọn tí kò yọ̀, kí àwọn tó ń rà dà bí àwọn tí kò ní, 31 kí àwọn tó ń lo ayé dà bí àwọn tí kò lò ó dé ẹ̀kúnrẹ́rẹ́; nítorí ìrísí* ayé yìí ń yí pa dà. 32 Ní tòótọ́, mi ò fẹ́ kí ẹ máa ṣàníyàn. Ọkùnrin tí kò gbéyàwó máa ń ṣàníyàn nípa àwọn ohun ti Olúwa, bó ṣe máa rí ìtẹ́wọ́gbà Olúwa. 33 Àmọ́ ọkùnrin tó gbéyàwó máa ń ṣàníyàn nípa àwọn ohun ti ayé,+ bó ṣe máa rí ìtẹ́wọ́gbà aya rẹ̀, 34 ó sì ní ìpínyà ọkàn. Yàtọ̀ síyẹn, obìnrin tí kò lọ́kọ àti wúńdíá, máa ń ṣàníyàn nípa àwọn ohun ti Olúwa,+ kí ó lè jẹ́ mímọ́ nínú ara àti nínú ẹ̀mí. Àmọ́, obìnrin tó ti lọ́kọ máa ń ṣàníyàn nípa àwọn ohun ti ayé, bó ṣe máa rí ìtẹ́wọ́gbà ọkọ rẹ̀. 35 mò ń sọ èyí nítorí àǹfààní ara yín, kì í ṣe kí n lè dín òmìnira yín kù,* àmọ́ kí n lè mú kí ẹ ṣe ohun tí ó tọ́, kí ẹ sì lè gbájú mọ́ iṣẹ́ Olúwa láìsí ìpínyà ọkàn.

36 Àmọ́ tí ẹnì kan bá rí i pé òun ti ń hùwà tí kò yẹ torí pé òun kò gbéyàwó,* tí onítọ̀hún sì ti kọjá ìgbà ìtànná èwe,* ohun tó yẹ kó ṣe nìyí: Kí ó ṣe ohun tí ó fẹ́; kò dẹ́ṣẹ̀. Kí wọ́n gbéyàwó.+ 37 Àmọ́ tí ẹnikẹ́ni bá ti pinnu nínú ọkàn rẹ̀, tí kò sì sídìí tó fi gbọ́dọ̀ yí i pa dà, ṣùgbọ́n tó ní àṣẹ lórí ohun tó fẹ́, tó sì ti pinnu nínú ọkàn rẹ̀ láti wà láìgbéyàwó,* yóò ṣe dáadáa.+ 38 Bákan náà, ẹni tó bá gbéyàwó* ṣe dáadáa, àmọ́ ẹni tí kò bá gbéyàwó ṣe dáadáa jù.+

39 Òfin de aya ní gbogbo ìgbà tí ọkọ rẹ̀ bá wà láàyè.+ Àmọ́ tí ọkọ rẹ̀ bá sùn nínú ikú, ó ní òmìnira láti ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú ẹni tó bá wù ú, kìkì nínú Olúwa.+ 40 Àmọ́ lérò tèmi, ó máa láyọ̀ jù tó bá wà bó ṣe wà; ó sì dá mi lójú pé èmi náà ní ẹ̀mí Ọlọ́run.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́