ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 27
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Jèhófà pa Léfíátánì (1)

      • Orin tó fi Ísírẹ́lì wé ọgbà àjàrà (2-13)

Àìsáyà 27:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:41; Jer 47:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 21

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 283-284

Àìsáyà 27:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó jọ pé Ísírẹ́lì ló ń tọ́ka sí, ó pè é ní obìnrin, ó sì fi wé ọgbà àjàrà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 80:8; Ais 5:1; Jer 2:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 21-22

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 284-286

Àìsáyà 27:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 33:29
  • +Ais 35:6; 41:18; 58:11
  • +Sm 121:4; Ais 46:3, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 21-22

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 284-286

Àìsáyà 27:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 85:2, 3; Ais 12:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 22

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 286

Àìsáyà 27:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 22

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 286

Àìsáyà 27:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 39:25; Ho 14:5
  • +Ais 60:21, 22; Jer 30:18, 19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 22

    7/1/1995, ojú ìwé 21

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 286

Àìsáyà 27:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 4:11; Isk 13:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 285

Àìsáyà 27:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 4:4; 48:10
  • +Mik 5:13, 14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 285

Àìsáyà 27:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 6:11, 12; Jer 26:18; Ida 2:5; Isk 36:4
  • +Ais 32:14

Àìsáyà 27:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:28; Ais 1:3; Jer 4:22; Ho 4:6
  • +2Kr 36:15, 16; Isk 9:9, 10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 285

Àìsáyà 27:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, odò Yúfírétì.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 34:2, 5
  • +Di 30:3; Ne 1:9; Ais 11:11, 12; Emọ 9:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 285

Àìsáyà 27:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 49:22; 62:10
  • +2Ọb 17:6; Ais 11:16; Ho 9:3
  • +Jer 43:4, 7; Sek 10:10
  • +Ais 2:3; 25:6; 52:1; Jer 3:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 285

Àwọn míì

Àìsá. 27:1Di 32:41; Jer 47:6
Àìsá. 27:2Sm 80:8; Ais 5:1; Jer 2:21
Àìsá. 27:3Di 33:29
Àìsá. 27:3Ais 35:6; 41:18; 58:11
Àìsá. 27:3Sm 121:4; Ais 46:3, 4
Àìsá. 27:4Sm 85:2, 3; Ais 12:1
Àìsá. 27:6Isk 39:25; Ho 14:5
Àìsá. 27:6Ais 60:21, 22; Jer 30:18, 19
Àìsá. 27:8Jer 4:11; Isk 13:13
Àìsá. 27:9Ais 4:4; 48:10
Àìsá. 27:9Mik 5:13, 14
Àìsá. 27:10Ais 6:11, 12; Jer 26:18; Ida 2:5; Isk 36:4
Àìsá. 27:10Ais 32:14
Àìsá. 27:11Di 32:28; Ais 1:3; Jer 4:22; Ho 4:6
Àìsá. 27:112Kr 36:15, 16; Isk 9:9, 10
Àìsá. 27:12Nọ 34:2, 5
Àìsá. 27:12Di 30:3; Ne 1:9; Ais 11:11, 12; Emọ 9:14
Àìsá. 27:13Ais 49:22; 62:10
Àìsá. 27:132Ọb 17:6; Ais 11:16; Ho 9:3
Àìsá. 27:13Jer 43:4, 7; Sek 10:10
Àìsá. 27:13Ais 2:3; 25:6; 52:1; Jer 3:17
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 27:1-13

Àìsáyà

27 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà, tòun ti idà rẹ̀ tó mú, tó tóbi, tó sì lágbára,+

Máa yíjú sí Léfíátánì,* ejò tó ń yọ́ bọ́rọ́,

Sí Léfíátánì, ejò tó ń lọ́,

Ó sì máa pa ẹran ńlá tó wà nínú òkun.

 2 Ní ọjọ́ yẹn, ẹ kọrin fún obìnrin náà* pé:

“Ọgbà àjàrà tí wáìnì rẹ̀ ń yọ ìfófòó!+

 3 Èmi, Jèhófà ń dáàbò bò ó.+

Gbogbo ìgbà ni mò ń bomi rin ín.+

Mò ń dáàbò bò ó tọ̀sántòru,

Kí ẹnikẹ́ni má bàa ṣe é léṣe.+

 4 Mi ò bínú rárá.+

Ta ló máa wá fi àwọn igi ẹlẹ́gùn-ún àti èpò bá mi jagun?

Gbogbo wọn ni màá tẹ̀ mọ́lẹ̀, tí màá sì dáná sun pa pọ̀.

 5 Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, jẹ́ kó rọ̀ mọ́ ibi ààbò mi.

Kó wá bá mi ṣàdéhùn àlàáfíà;

Àní kó wá àlàáfíà pẹ̀lú mi.”

 6 Lọ́jọ́ iwájú, Jékọ́bù máa ta gbòǹgbò,

Ísírẹ́lì máa yọ ìtànná, ó máa rú jáde,+

Wọ́n sì máa fi irè oko kún ilẹ̀ náà.+

 7 Ṣé dandan ni kí a fi ẹgba ẹni tó ń lù ú nà án ni?

Àbí ṣé dandan ni kí a pa á bí àwọn èèyàn rẹ̀ tí wọ́n pa?

 8 Igbe tó ń dẹ́rù bani lo máa fi bá a fà á nígbà tí o bá lé e lọ.

Atẹ́gùn rẹ̀ tó le ló máa fi lé e jáde ní ọjọ́ afẹ́fẹ́ ìlà oòrùn.+

 9 Torí náà, báyìí la ṣe máa ṣètùtù fún ẹ̀ṣẹ̀ Jékọ́bù,+

Èyí sì ni ohun tó máa jèrè lẹ́kùn-ún rẹ́rẹ́ nígbà tí a bá mú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ kúrò:

Ó máa ṣe gbogbo òkúta pẹpẹ

Bí òkúta ẹfun tí wọ́n lọ̀ lúúlúú,

Òpó òrìṣà* àti pẹpẹ tùràrí kankan ò sì ní ṣẹ́ kù.+

10 Torí wọ́n máa pa ìlú olódi tì;

Wọ́n máa pa àwọn ibi ìjẹko tì, wọ́n á sì fi í sílẹ̀ bí aginjù.+

Ibẹ̀ ni ọmọ màlúù á ti máa jẹko, tó sì máa dùbúlẹ̀ sí,

Ó sì máa jẹ àwọn ẹ̀ka rẹ̀.+

11 Nígbà tí àwọn ẹ̀ka igi rẹ̀ bá ti gbẹ,

Àwọn obìnrin máa wá ṣẹ́ wọn,

Wọ́n á sì fi dáná.

Torí àwọn èèyàn yìí ò ní òye.+

Ìdí nìyẹn tí Aṣẹ̀dá wọn ò fi ní ṣàánú wọn rárá,

Ẹni tó dá wọn ò sì ní ṣojúure kankan sí wọn.+

12 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà máa lu èso jáde láti Odò* tó ń ṣàn títí dé Àfonífojì Íjíbítì,+ a sì máa kó yín jọ ní ọ̀kọ̀ọ̀kan, ẹ̀yin èèyàn Ísírẹ́lì.+ 13 Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n máa fun ìwo ńlá kan,+ àwọn tó ń ṣègbé lọ ní ilẹ̀ Ásíríà+ àti àwọn tó fọ́n ká ní ilẹ̀ Íjíbítì+ máa wá, wọ́n á sì forí balẹ̀ fún Jèhófà ní òkè mímọ́, ní Jerúsálẹ́mù.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́