ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Émọ́sì 6
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Émọ́sì

      • Ẹ gbé! Ẹ̀yin tí ẹ kò mikàn (1-14)

        • Ibùsùn tí wọ́n fi eyín erin ṣe; abọ́ wáìnì (4, 6)

Émọ́sì 6:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tí kò mikàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Emọ 3:13, 15

Émọ́sì 6:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó ṣe kedere pé àwọn ìjọba ilẹ̀ Júdà àti ti Ísírẹ́lì ló ń tọ́ka sí.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 34:2, 8; 2Ọb 14:28

Émọ́sì 6:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “jókòó.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 56:12
  • +Emọ 5:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2004, ojú ìwé 21

Émọ́sì 6:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọn akọ ọmọ màlúù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 22:39
  • +Emọ 3:12
  • +Ais 22:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2004, ojú ìwé 20-21

    3/15/2003, ojú ìwé 16-17

Émọ́sì 6:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 5:12
  • +2Kr 7:6; 29:25, 26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2004, ojú ìwé 20-21

Émọ́sì 6:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “kò mú wọn ṣàìsàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 5:11
  • +2Ọb 15:29; 17:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2004, ojú ìwé 20-21

    3/15/2003, ojú ìwé 16-17

Émọ́sì 6:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:41; Emọ 5:5

Émọ́sì 6:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Emọ 4:2
  • +Isk 33:28; Ho 5:5
  • +Ida 2:5
  • +Mik 1:6

Émọ́sì 6:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Arákùnrin bàbá rẹ̀.”

Émọ́sì 6:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 10:5, 6
  • +Emọ 3:15

Émọ́sì 6:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìkorò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 21:13; Ais 59:13; Ho 10:4; Emọ 5:7

Émọ́sì 6:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “la fi gba àwọn ìwo fún ara wa.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 8:17, 18; Sm 75:5

Émọ́sì 6:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àbáwọlé Hámátì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:49, 50; 2Ọb 15:29; 17:6; Ais 7:20; 8:4; 10:5, 6; Ho 10:6
  • +Nọ 34:2, 8

Àwọn míì

Émọ́sì 6:1Emọ 3:13, 15
Émọ́sì 6:2Nọ 34:2, 8; 2Ọb 14:28
Émọ́sì 6:3Ais 56:12
Émọ́sì 6:3Emọ 5:12
Émọ́sì 6:41Ọb 22:39
Émọ́sì 6:4Emọ 3:12
Émọ́sì 6:4Ais 22:13
Émọ́sì 6:5Ais 5:12
Émọ́sì 6:52Kr 7:6; 29:25, 26
Émọ́sì 6:6Ais 5:11
Émọ́sì 6:62Ọb 15:29; 17:6
Émọ́sì 6:7Di 28:41; Emọ 5:5
Émọ́sì 6:8Emọ 4:2
Émọ́sì 6:8Isk 33:28; Ho 5:5
Émọ́sì 6:8Ida 2:5
Émọ́sì 6:8Mik 1:6
Émọ́sì 6:11Ais 10:5, 6
Émọ́sì 6:11Emọ 3:15
Émọ́sì 6:121Ọb 21:13; Ais 59:13; Ho 10:4; Emọ 5:7
Émọ́sì 6:13Di 8:17, 18; Sm 75:5
Émọ́sì 6:14Di 28:49, 50; 2Ọb 15:29; 17:6; Ais 7:20; 8:4; 10:5, 6; Ho 10:6
Émọ́sì 6:14Nọ 34:2, 8
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Émọ́sì 6:1-14

Émọ́sì

6 “Àwọn tó dá ara wọn lójú* ní Síónì gbé!

Àwọn tí ọkàn wọn balẹ̀ lórí òkè Samáríà,+

Àwọn olókìkí èèyàn nínú àwọn orílẹ̀-èdè tó gba iwájú,

Àwọn tí ilé Ísírẹ́lì ń lọ sọ́dọ̀ wọn!

 2 Ẹ ré kọjá sí Kálínè, kí ẹ sì wò.

Ẹ ti ibẹ̀ lọ sí Hámátì Ńlá,+

Kí ẹ sì lọ sí Gátì ti àwọn Filísínì.

Ṣé wọ́n sàn ju àwọn ìjọba yìí,*

Tàbí ṣé ilẹ̀ wọn tóbi ju tiyín lọ ni?

 3 Ṣé ẹ̀ ń mú ọjọ́ àjálù kúrò lọ́kàn yín+

Tí ẹ sì ń mú kí ìwà ipá jọba* láàárín yín?+

 4 Wọ́n ń dùbúlẹ̀ sórí àwọn ibùsùn tí wọ́n fi eyín erin ṣe,+ wọ́n sì ń nà gbalaja sórí àga tìmùtìmù,+

Wọ́n ń jẹ àwọn àgbò inú agbo ẹran àti àwọn ọmọ màlúù* tí wọ́n bọ́ sanra;+

 5 Wọ́n ń kọ orin sí ìró háàpù,*+

Bíi Dáfídì, wọ́n ṣe àwọn ohun èlò ìkọrin;+

 6 Wọ́n ń fi abọ́ mu wáìnì+

Wọ́n sì ń fi òróró tó dára jù lọ para.

Àmọ́ àjálù tó dé bá Jósẹ́fù kò dùn wọ́n.*+

 7 Nítorí náà, àwọn ló máa kọ́kọ́ lọ sí ìgbèkùn,+

Àríyá aláriwo àwọn tó nà gbalaja sì máa dópin.

 8 ‘Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ ti fi ara* rẹ̀ búra,’+ àní Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé,

‘“Mo kórìíra ìgbéraga Jékọ́bù,+

Mo sì kórìíra àwọn ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò,+

Màá sì fa ìlú náà àti ohun tó wà nínú rẹ̀ lé àwọn ọ̀tá lọ́wọ́.+

9 “‘“Bí ó bá sì ṣẹ́ ku ọkùnrin mẹ́wàá sínú ilé kan, àwọn náà máa kú. 10 Mọ̀lẹ́bí* kan á wá gbé wọn jáde, á sì sun wọ́n lọ́kọ̀ọ̀kan. Á kó egungun wọn jáde kúrò nínú ilé; á sì béèrè lọ́wọ́ ẹni tó bá wà ní àwọn yàrá inú pé, ‘Ṣé wọ́n ṣì kù lọ́dọ̀ rẹ?’ Ẹni náà á fèsì pé, ‘Kò sí ẹnì kankan!’ Nígbà náà, á sọ pé, ‘Dákẹ́! Nítorí kì í ṣe àkókò yìí ló yẹ ká máa pe Jèhófà.’”

11 Nítorí Jèhófà ló ń pàṣẹ,+

Á wó ilé ńlá lulẹ̀ di àlàpà,

Á sì fọ́ ilé kékeré túútúú.+

12 Ǹjẹ́ àwọn ẹṣin máa ń sáré lórí àpáta,

Àbí ẹnikẹ́ni lè fi màlúù túlẹ̀ lórí rẹ̀?

Nítorí ẹ ti sọ ìdájọ́ òdodo di igi onímájèlé,

Ẹ sì ti sọ èso òdodo di iwọ.*+

13 Ẹ̀ ń yọ̀ lórí nǹkan tí kò ní láárí,

Ẹ sì ń sọ pé, “Ǹjẹ́ kì í ṣe okun wa ló mú ká di alágbára?”*+

14 Nítorí náà, ẹ̀yin èèyàn ilé Ísírẹ́lì, màá gbé orílẹ̀-èdè kan dìde sí yín’+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí,

‘Wọ́n á sì ni yín lára láti Lebo-hámátì*+ títí dé Àfonífojì Árábà.’”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́