ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 45
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jeremáyà

      • Iṣẹ́ tí Jèhófà rán sí Bárúkù (1-5)

Jeremáyà 45:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 32:12; 43:3
  • +Jer 36:4, 32
  • +Jer 25:1; 36:1

Jeremáyà 45:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jeremáyà, ojú ìwé 103, 105

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2006, ojú ìwé 17

    8/15/1997, ojú ìwé 21

Jeremáyà 45:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 5:5; Jer 1:1, 10

Jeremáyà 45:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “retí.”

  • *

    Ní Héb., “ẹlẹ́ran ara.”

  • *

    Tàbí “màá jẹ́ kí o sá àsálà fún ọkàn rẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 66:16; Jer 25:17, 26; Sef 3:8
  • +Jer 21:9; 39:18; 43:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jeremáyà, ojú ìwé 103-113

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2008, ojú ìwé 8-9

    4/15/2008, ojú ìwé 15

    8/15/2006, ojú ìwé 17-19

    10/1/2002, ojú ìwé 14-15

    2/15/2000, ojú ìwé 6

    8/15/1997, ojú ìwé 21

    Jí!,

    4/8/2003, ojú ìwé 31

Àwọn míì

Jer. 45:1Jer 32:12; 43:3
Jer. 45:1Jer 36:4, 32
Jer. 45:1Jer 25:1; 36:1
Jer. 45:4Ais 5:5; Jer 1:1, 10
Jer. 45:5Ais 66:16; Jer 25:17, 26; Sef 3:8
Jer. 45:5Jer 21:9; 39:18; 43:6
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jeremáyà 45:1-5

Jeremáyà

45 Ọ̀rọ̀ tí wòlíì Jeremáyà sọ fún Bárúkù+ ọmọ Neráyà nìyí, nígbà tó ń kọ ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà ń sọ fún un sínú ìwé+ ní ọdún kẹrin Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà:

2 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nípa rẹ nìyí, ìwọ Bárúkù, 3 ‘O sọ pé: “Mo gbé! Nítorí pé Jèhófà ti fi ẹ̀dùn ọkàn kún ìrora mi. Àárẹ̀ mú mi nítorí ìrora mi, mi ò sì rí ibi ìsinmi kankan.”’

4 “Kí o sọ fún un pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Wò ó! Ohun tí mo ti kọ́ ni màá ya lulẹ̀, ohun tí mo sì ti gbìn ni màá fà tu, ìyẹn gbogbo ilẹ̀ náà.+ 5 Ṣùgbọ́n ìwọ ń wá* àwọn ohun ńlá fún ara rẹ. Má ṣe wá wọn mọ́.”’

“‘Nítorí mo máa tó mú àjálù wá bá gbogbo èèyàn,’*+ ni Jèhófà wí, ‘àmọ́ màá jẹ́ kí o jèrè ẹ̀mí rẹ* ní ibikíbi tí o bá lọ.’”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́