ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Dáníẹ́lì 10
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Dáníẹ́lì

      • Ìránṣẹ́ Ọlọ́run bẹ Dáníẹ́lì wò (1-21)

        • Máíkẹ́lì ran áńgẹ́lì náà lọ́wọ́ (13)

Dáníẹ́lì 10:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 1:1, 2; Ais 45:1; Da 1:21; 6:28
  • +Da 1:7; 4:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 45, 198-200

Dáníẹ́lì 10:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 9:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 200-201

Dáníẹ́lì 10:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 200-201

Dáníẹ́lì 10:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Hídẹ́kẹ́lì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 2:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 201-202

Dáníẹ́lì 10:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aṣọ àtàtà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 19:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 201-203

Dáníẹ́lì 10:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 1:16
  • +Isk 1:5, 7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 202-203

Dáníẹ́lì 10:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 6:17; Iṣe 9:7

Dáníẹ́lì 10:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 7:28; 8:27

Dáníẹ́lì 10:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 8:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 203-205

Dáníẹ́lì 10:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 1:9; Ifi 1:17

Dáníẹ́lì 10:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fani mọ́ra gan-an; ọkùnrin pàtàkì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 9:23; 10:19

Dáníẹ́lì 10:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 1:17
  • +Da 9:23

Dáníẹ́lì 10:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Ta Ló Dà Bí Ọlọ́run?”

  • *

    Tàbí “ọmọ aládé onípò kìíní.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 6:12
  • +Da 10:21; 12:1; Jud 9; Ifi 12:7, 8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2011, ojú ìwé 8

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 204-205

Dáníẹ́lì 10:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 2:28
  • +Da 8:17, 26; 12:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2020, ojú ìwé 3

Dáníẹ́lì 10:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 206

Dáníẹ́lì 10:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 6:7; Jer 1:9
  • +Da 10:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 206-208

Dáníẹ́lì 10:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 6:22
  • +Ais 6:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 206-208

Dáníẹ́lì 10:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 10:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 208

Dáníẹ́lì 10:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fani mọ́ra gan-an; ọkùnrin pàtàkì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 1:17
  • +Da 9:22, 23; 10:11
  • +Ond 6:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 208

Dáníẹ́lì 10:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 10:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 204-205, 208

Dáníẹ́lì 10:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 10:13; Jud 9; Ifi 12:7, 8
  • +Da 12:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 204-205, 208

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 134

Àwọn míì

Dán. 10:1Ẹsr 1:1, 2; Ais 45:1; Da 1:21; 6:28
Dán. 10:1Da 1:7; 4:8
Dán. 10:2Da 9:3
Dán. 10:4Jẹ 2:14
Dán. 10:5Ifi 19:14
Dán. 10:6Isk 1:16
Dán. 10:6Isk 1:5, 7
Dán. 10:72Ọb 6:17; Iṣe 9:7
Dán. 10:8Da 7:28; 8:27
Dán. 10:9Da 8:18
Dán. 10:10Jer 1:9; Ifi 1:17
Dán. 10:11Da 9:23; 10:19
Dán. 10:12Ifi 1:17
Dán. 10:12Da 9:23
Dán. 10:13Ef 6:12
Dán. 10:13Da 10:21; 12:1; Jud 9; Ifi 12:7, 8
Dán. 10:14Da 2:28
Dán. 10:14Da 8:17, 26; 12:4
Dán. 10:16Ais 6:7; Jer 1:9
Dán. 10:16Da 10:8
Dán. 10:17Ond 6:22
Dán. 10:17Ais 6:5
Dán. 10:18Da 10:10
Dán. 10:19Ifi 1:17
Dán. 10:19Da 9:22, 23; 10:11
Dán. 10:19Ond 6:23
Dán. 10:20Da 10:13
Dán. 10:21Da 10:13; Jud 9; Ifi 12:7, 8
Dán. 10:21Da 12:1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Dáníẹ́lì 10:1-21

Dáníẹ́lì

10 Ní ọdún kẹta Kírúsì+ ọba Páṣíà, a ṣí ọ̀rọ̀ kan payá fún Dáníẹ́lì, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Bẹtiṣásárì;+ òótọ́ ni ọ̀rọ̀ náà, ó dá lórí ìjàkadì ńlá kan. Ọ̀rọ̀ náà yé e, a sì jẹ́ kí ohun tó rí yé e.

2 Nígbà yẹn, èmi Dáníẹ́lì ti ń ṣọ̀fọ̀+ fún ọ̀sẹ̀ mẹ́ta gbáko. 3 Mi ò jẹ oúnjẹ tó dọ́ṣọ̀, ẹran tàbí wáìnì kò kan ẹnu mi, mi ò sì fi òróró para rárá fún ọ̀sẹ̀ mẹ́ta gbáko. 4 Ní ọjọ́ kẹrìnlélógún, oṣù kìíní, nígbà tí mo wà létí odò ńlá náà, ìyẹn Tígírísì,*+ 5 mo wòkè, mo sì rí ọkùnrin kan tó wọ aṣọ ọ̀gbọ̀,*+ ó sì de àmùrè wúrà tó wá láti Úfásì mọ́ ìbàdí rẹ̀. 6 Ara rẹ̀ dà bíi kírísóláítì,+ ojú rẹ̀ rí bíi mànàmáná, ẹyinjú rẹ̀ dà bí ògùṣọ̀ oníná, apá rẹ̀ àti ẹsẹ̀ rẹ̀ dà bíi bàbà tó ń dán,+ ìró ọ̀rọ̀ rẹ̀ sì dà bí ìró èrò púpọ̀. 7 Èmi Dáníẹ́lì nìkan ni mo rí ìran náà; àwọn ọkùnrin tó wà lọ́dọ̀ mi ò rí ìran náà.+ Síbẹ̀, ẹ̀rù bà wọ́n gidigidi, wọ́n sá lọ, wọ́n sì fara pa mọ́.

8 Ó wá ku èmi nìkan, nígbà tí mo sì rí ìran ńlá yìí, agbára kankan ò ṣẹ́ kù nínú mi, ojú mi tó fani mọ́ra tẹ́lẹ̀ yí pa dà, mi ò sì lókun mọ́ rárá.+ 9 Mo wá gbọ́ tó ń sọ̀rọ̀; àmọ́ nígbà tí mo gbọ́ tó ń sọ̀rọ̀, mo sùn lọ fọnfọn ní ìdojúbolẹ̀.+ 10 Ọwọ́ kan sì kàn mí,+ ó jí mi pé kí n dìde lórí ọwọ́ mi àti orúnkún mi. 11 Ó wá sọ fún mi pé:

“Dáníẹ́lì, ìwọ ọkùnrin tó ṣeyebíye gan-an,*+ fiyè sí ọ̀rọ̀ tí mo fẹ́ sọ fún ọ. Ó yá, dìde níbi tí o wà, torí a ti rán mi sí ọ.”

Nígbà tó sọ ọ̀rọ̀ yìí fún mi, mo dìde, mo bẹ̀rẹ̀ sí í gbọ̀n.

12 Ó wá sọ fún mi pé: “Má bẹ̀rù,+ ìwọ Dáníẹ́lì. A ti gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ láti ọjọ́ tí o ti kọ́kọ́ jẹ́ kí ọkàn rẹ lóye, tí o ti rẹ ara rẹ sílẹ̀ níwájú Ọlọ́run rẹ, torí ọ̀rọ̀ rẹ ni mo sì ṣe wá.+ 13 Àmọ́ olórí+ ilẹ̀ ọba Páṣíà dí mi lọ́nà fún ọjọ́ mọ́kànlélógún (21). Ṣùgbọ́n Máíkẹ́lì,*+ ọ̀kan nínú àwọn ọmọ aládé tí ipò wọn ga jù* wá ràn mí lọ́wọ́; mo sì wà níbẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn ọba Páṣíà. 14 Mo wá láti jẹ́ kí o lóye ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí àwọn èèyàn rẹ ní àkókò òpin,+ torí ìran ohun tó ṣì máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú ni.”+

15 Nígbà tó bá mi sọ àwọn ọ̀rọ̀ yìí, mo dojú bolẹ̀, mi ò sì lè sọ̀rọ̀. 16 Ẹnì kan tó rí bí èèyàn wá fọwọ́ kan ètè mi,+ mo sì la ẹnu mi, mo sọ fún ẹni tó dúró níwájú mi pé: “Olúwa mi, ìran náà ń kó jìnnìjìnnì bá mi, mi ò sì lókun rárá.+ 17 Báwo ni ìránṣẹ́ olúwa mi ṣe wá fẹ́ bá olúwa mi sọ̀rọ̀?+ Mi ò lókun kankan báyìí, èémí kankan ò sì ṣẹ́ kù nínú mi.”+

18 Ẹni tó rí bí èèyàn náà tún fọwọ́ kàn mí, ó sì fún mi lókun.+ 19 Lẹ́yìn náà, ó sọ pé: “Má bẹ̀rù,+ ìwọ ọkùnrin tó ṣeyebíye gan-an.*+ Kí o ní àlàáfíà.+ Jẹ́ alágbára, àní kí o jẹ́ alágbára.” Bó ṣe ń bá mi sọ̀rọ̀, mo lókun, mo sì sọ pé: “Kí olúwa mi sọ̀rọ̀, torí o ti fún mi lókun.”

20 Ó wá sọ pé: “Ṣé o mọ ìdí tí mo fi wá bá ọ? Ní báyìí, màá pa dà lọ bá olórí Páṣíà jà.+ Tí mo bá kúrò, olórí ilẹ̀ Gíríìsì máa wá. 21 Àmọ́, màá sọ àwọn nǹkan tí a kọ sínú ìwé òtítọ́ fún ọ. Kò sí ẹni tó ń tì mí lẹ́yìn gbágbáágbá nínú àwọn nǹkan yìí, àfi Máíkẹ́lì,+ olórí yín.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́