ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 31
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ẹ́kísódù

      • Ọlọ́run fi ẹ̀mí rẹ̀ kún inú àwọn oníṣẹ́ ọnà (1-11)

      • Sábáàtì jẹ́ àmì láàárín Ọlọ́run àti Ísírẹ́lì (12-17)

      • Wàláà òkúta méjì (18)

Ẹ́kísódù 31:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “fi orúkọ pe.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 37:1
  • +Ẹk 35:30-34; 1Kr 2:20

Ẹ́kísódù 31:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 28:9-11
  • +2Kr 2:13, 14

Ẹ́kísódù 31:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “jẹ́ ọlọgbọ́n ní ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 38:23
  • +Ẹk 36:1

Ẹ́kísódù 31:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 36:8
  • +Ẹk 37:1
  • +Ẹk 37:6

Ẹ́kísódù 31:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 37:10
  • +Ẹk 37:17, 24
  • +Ẹk 37:25

Ẹ́kísódù 31:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 38:1; 40:6
  • +Ẹk 30:18; 38:8

Ẹ́kísódù 31:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 28:2, 15; 39:1, 27; Le 8:7

Ẹ́kísódù 31:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 30:25, 35; 37:29

Ẹ́kísódù 31:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 20:8; Le 19:30; Kol 2:16, 17

Ẹ́kísódù 31:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 5:12
  • +Ẹk 35:2; Nọ 15:32, 35

Ẹ́kísódù 31:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 16:23; 20:10

Ẹ́kísódù 31:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 31:13
  • +Jẹ 2:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2019, ojú ìwé 3

Ẹ́kísódù 31:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 24:12; 32:15; Di 4:13; 9:15
  • +Mt 12:28; Lk 11:20; 2Kọ 3:3

Àwọn míì

Ẹ́kís. 31:2Ẹk 37:1
Ẹ́kís. 31:2Ẹk 35:30-34; 1Kr 2:20
Ẹ́kís. 31:5Ẹk 28:9-11
Ẹ́kís. 31:52Kr 2:13, 14
Ẹ́kís. 31:6Ẹk 38:23
Ẹ́kís. 31:6Ẹk 36:1
Ẹ́kís. 31:7Ẹk 36:8
Ẹ́kís. 31:7Ẹk 37:1
Ẹ́kís. 31:7Ẹk 37:6
Ẹ́kís. 31:8Ẹk 37:10
Ẹ́kís. 31:8Ẹk 37:17, 24
Ẹ́kís. 31:8Ẹk 37:25
Ẹ́kís. 31:9Ẹk 38:1; 40:6
Ẹ́kís. 31:9Ẹk 30:18; 38:8
Ẹ́kís. 31:10Ẹk 28:2, 15; 39:1, 27; Le 8:7
Ẹ́kís. 31:11Ẹk 30:25, 35; 37:29
Ẹ́kís. 31:13Ẹk 20:8; Le 19:30; Kol 2:16, 17
Ẹ́kís. 31:14Di 5:12
Ẹ́kís. 31:14Ẹk 35:2; Nọ 15:32, 35
Ẹ́kís. 31:15Ẹk 16:23; 20:10
Ẹ́kís. 31:17Ẹk 31:13
Ẹ́kís. 31:17Jẹ 2:2
Ẹ́kís. 31:18Ẹk 24:12; 32:15; Di 4:13; 9:15
Ẹ́kís. 31:18Mt 12:28; Lk 11:20; 2Kọ 3:3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Ẹ́kísódù 31:1-18

Ẹ́kísódù

31 Jèhófà ń bá ọ̀rọ̀ tó ń sọ fún Mósè lọ pé: 2 “Wò ó, mo ti yan* Bẹ́sálẹ́lì+ ọmọ Úráì ọmọ Húrì látinú ẹ̀yà Júdà.+ 3 Màá fi ẹ̀mí Ọlọ́run kún inú rẹ̀, màá fún un ní ọgbọ́n, òye àti ìmọ̀ nípa onírúurú iṣẹ́ ọnà, 4 kó lè ṣe iṣẹ́ ọnà ayàwòrán, kó lè fi wúrà, fàdákà àti bàbà ṣiṣẹ́, 5 kó lè gé òkúta, kó sì tò ó,+ kó sì lè fi igi ṣe onírúurú nǹkan.+ 6 Bákan náà, mo ti yan Òhólíábù  + ọmọ Áhísámákì látinú ẹ̀yà Dánì kó lè ràn án lọ́wọ́, màá sì fi ọgbọ́n sínú ọkàn gbogbo àwọn tó mọṣẹ́,* kí wọ́n lè ṣe gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ:+ 7 àgọ́ ìpàdé,+ àpótí Ẹ̀rí+ àti ìbòrí rẹ̀,+ gbogbo ohun èlò àgọ́ náà, 8 tábìlì+ àti àwọn ohun èlò rẹ̀, ọ̀pá fìtílà tí wọ́n fi ògidì wúrà ṣe àti gbogbo ohun èlò rẹ̀,+ pẹpẹ tùràrí,+ 9 pẹpẹ ẹbọ sísun+ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀, bàsíà àti ẹsẹ̀ rẹ̀,+ 10 àwọn aṣọ tí wọ́n hun dáadáa, aṣọ mímọ́ ti àlùfáà Áárónì, aṣọ tí àwọn ọmọ rẹ̀ máa fi ṣiṣẹ́ àlùfáà,+ 11 òróró àfiyanni àti tùràrí onílọ́fínńdà fún ibi mímọ́.+ Kí wọ́n ṣe gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ.”

12 Jèhófà tún sọ fún Mósè pé: 13 “Bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọ̀rọ̀, kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Ó ṣe pàtàkì pé kí ẹ pa àwọn sábáàtì mi mọ́,+ torí ó jẹ́ àmì láàárín èmi àti ẹ̀yin ní ìrandíran yín, kí ẹ lè mọ̀ pé èmi Jèhófà ló ń sọ yín di mímọ́. 14 Kí ẹ pa Sábáàtì mọ́, torí ohun mímọ́ ló jẹ́ fún yín.+ Ṣe ni kí ẹ pa ẹnikẹ́ni tó bá sọ ọ́ di aláìmọ́. Tí ẹnikẹ́ni bá ṣiṣẹ́ kankan lọ́jọ́ náà, kí ẹ pa ẹni* náà, kí ẹ lè mú un kúrò nínú àwọn èèyàn rẹ̀.+ 15 Ọjọ́ mẹ́fà ni kí ẹ fi ṣiṣẹ́, àmọ́ kí ọjọ́ keje jẹ́ sábáàtì, ọjọ́ ìsinmi tí ẹ ò ní ṣiṣẹ́ rárá.+ Ohun mímọ́ ló jẹ́ fún Jèhófà. Ṣe ni kí ẹ pa ẹnikẹ́ni tó bá ṣiṣẹ́ ní ọjọ́ Sábáàtì. 16 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbọ́dọ̀ pa Sábáàtì mọ́; wọ́n gbọ́dọ̀ máa pa Sábáàtì mọ́ jálẹ̀ gbogbo ìran wọn. Májẹ̀mú tó máa wà títí lọ ni. 17 Ó jẹ́ àmì tó máa wà pẹ́ títí láàárín èmi àtàwọn ọmọ Ísírẹ́lì,+ torí ọjọ́ mẹ́fà ni Jèhófà fi dá ọ̀run àti ayé, ó wá sinmi ní ọjọ́ keje, ara sì tù ú.’”+

18 Gbàrà tó bá a sọ̀rọ̀ tán lórí Òkè Sínáì, ó fún Mósè ní wàláà Ẹ̀rí méjì,+ àwọn wàláà òkúta tí ìka Ọlọ́run+ kọ̀wé sí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́