ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Tímótì 2
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Tímótì

      • Gbàdúrà nítorí onírúurú èèyàn (1-7)

        • Ọlọ́run kan, alárinà kan (5)

        • Ìràpadà tó bá a mu rẹ́gí fún gbogbo èèyàn (6)

      • Àwọn ìtọ́ni fún tọkùnrin tobìnrin (8-15)

        • Múra lọ́nà tó bójú mu (9, 10)

1 Tímótì 2:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    5/1/1996, ojú ìwé 20

1 Tímótì 2:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ipò àṣẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 5:44
  • +Jer 29:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2020, ojú ìwé 15

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    5/1/1996, ojú ìwé 20

    9/15/1993, ojú ìwé 15

1 Tímótì 2:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jud 25

1 Tímótì 2:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 45:22; Iṣe 17:30; Ro 5:18; 1Ti 4:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 47

1 Tímótì 2:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 6:4; Ro 3:30
  • +Heb 8:6; 9:15
  • +1Kọ 11:25
  • +Iṣe 4:12; Ro 5:15; 2Ti 1:9, 10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 27

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2008, ojú ìwé 13-14

    2/15/1991, ojú ìwé 17

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 10-11

1 Tímótì 2:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “gbogbo onírúurú èèyàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 20:28; Mk 10:45; Kol 1:13, 14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 27

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 142-143

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2011, ojú ìwé 13

    4/15/1999, ojú ìwé 12

    7/15/1997, ojú ìwé 6-7

    6/15/1992, ojú ìwé 5-6

    2/15/1991, ojú ìwé 12-13, 17

    Mẹtalọkan, ojú ìwé 15

    Ayọ, ojú ìwé 107

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 188-189

1 Tímótì 2:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 9:15
  • +Ga 2:7, 8
  • +Ga 1:15, 16

1 Tímótì 2:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “ọwọ́ ìdúróṣinṣin.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 141:2
  • +Jem 1:20
  • +Flp 2:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2002, ojú ìwé 19

    11/15/1992, ojú ìwé 23

1 Tímótì 2:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tó buyì kúnni.”

  • *

    Tàbí “làákàyè; òye.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 3:3, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 52

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2016, ojú ìwé 16-17

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2015, ojú ìwé 9

    2/15/2009, ojú ìwé 20-21

    5/1/2005, ojú ìwé 29

    12/1/2003, ojú ìwé 22

    8/1/2002, ojú ìwé 17-18

    8/15/1992, ojú ìwé 14

    6/1/1991, ojú ìwé 30

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 56-57

    Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 8

    Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, ojú ìwé 79

    Jí!,

    10/8/2005, ojú ìwé 27

    8/8/1998, ojú ìwé 17

    Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 131-132

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    9/1996, ojú ìwé 4-5

    Yiyan, ojú ìwé 80

1 Tímótì 2:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 31:30

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 52

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2016, ojú ìwé 16-17

    Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 8

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2005, ojú ìwé 29

    12/1/2003, ojú ìwé 22

    8/1/2002, ojú ìwé 17-18

    Jí!,

    10/8/2005, ojú ìwé 27

    Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 131-132

1 Tímótì 2:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “láìsọ̀rọ̀; fara balẹ̀ kẹ́kọ̀ọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 5:24

1 Tímótì 2:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “máa fara balẹ̀; máa wà ní ìdákẹ́jẹ́ẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 14:34

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2007, ojú ìwé 4

1 Tímótì 2:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 2:18, 22; 1Kọ 11:8

1 Tímótì 2:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 3:6, 13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2020, ojú ìwé 4

    Jí!,

    9/8/1998, ojú ìwé 24

1 Tímótì 2:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “tí wọ́n.”

  • *

    Tàbí “làákàyè; òye.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 5:14
  • +1Ti 2:9, 10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2017, ojú ìwé 6

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2008, ojú ìwé 30

    5/1/2005, ojú ìwé 29

    1/15/1991, ojú ìwé 30

Àwọn míì

1 Tím. 2:2Mt 5:44
1 Tím. 2:2Jer 29:7
1 Tím. 2:3Jud 25
1 Tím. 2:4Ais 45:22; Iṣe 17:30; Ro 5:18; 1Ti 4:10
1 Tím. 2:5Di 6:4; Ro 3:30
1 Tím. 2:5Heb 8:6; 9:15
1 Tím. 2:51Kọ 11:25
1 Tím. 2:5Iṣe 4:12; Ro 5:15; 2Ti 1:9, 10
1 Tím. 2:6Mt 20:28; Mk 10:45; Kol 1:13, 14
1 Tím. 2:7Iṣe 9:15
1 Tím. 2:7Ga 2:7, 8
1 Tím. 2:7Ga 1:15, 16
1 Tím. 2:8Sm 141:2
1 Tím. 2:8Jem 1:20
1 Tím. 2:8Flp 2:14
1 Tím. 2:91Pe 3:3, 4
1 Tím. 2:10Owe 31:30
1 Tím. 2:11Ef 5:24
1 Tím. 2:121Kọ 14:34
1 Tím. 2:13Jẹ 2:18, 22; 1Kọ 11:8
1 Tím. 2:14Jẹ 3:6, 13
1 Tím. 2:151Ti 5:14
1 Tím. 2:151Ti 2:9, 10
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Tímótì 2:1-15

Ìwé Kìíní sí Tímótì

2 Torí náà, mò ń pàrọwà fún yín ṣáájú ohun gbogbo pé kí ẹ máa rawọ́ ẹ̀bẹ̀, kí ẹ máa gbàdúrà, kí ẹ máa dúpẹ́, kí ẹ sì máa bẹ̀bẹ̀ torí onírúurú èèyàn, 2 kí ẹ ṣe bẹ́ẹ̀ torí àwọn ọba àti gbogbo àwọn tó wà ní ipò gíga,*+ ká lè máa gbé ìgbé ayé tó pa rọ́rọ́ nìṣó pẹ̀lú ìbàlẹ̀ ọkàn, bí a ti ń fi gbogbo ọkàn wa sin Ọlọ́run, tí a sì ń fọwọ́ pàtàkì mú nǹkan.+ 3 Èyí dáa, ó sì ní ìtẹ́wọ́gbà lójú Ọlọ́run, Olùgbàlà wa,+ 4 ẹni tó fẹ́ ká gba onírúurú èèyàn là,+ kí wọ́n sì ní ìmọ̀ tó péye nípa òtítọ́. 5 Torí Ọlọ́run kan ló wà+ àti alárinà kan+ láàárín Ọlọ́run àtàwọn èèyàn,+ ọkùnrin kan, Kristi Jésù,+ 6 ẹni tó fi ara rẹ̀ ṣe ìràpadà tó bá a mu rẹ́gí fún gbogbo èèyàn*+—ohun tí a máa jẹ́rìí sí nìyí tí àkókò rẹ̀ bá tó. 7 Torí ìjẹ́rìí yìí  + ni a ṣe yàn mí láti jẹ́ oníwàásù àti àpọ́sítélì+—òótọ́ ni mò ń sọ, mi ò parọ́—olùkọ́ àwọn orílẹ̀-èdè+ ní ọ̀rọ̀ ìgbàgbọ́ àti òtítọ́.

8 Nítorí náà, ní ibi gbogbo mo fẹ́ kí àwọn ọkùnrin máa gbàdúrà, kí wọ́n máa gbé ọwọ́ mímọ́* sókè,+ láìsí ìbínú+ àti fífa ọ̀rọ̀.+ 9 Bákan náà, kí àwọn obìnrin máa fi aṣọ tó bójú mu* ṣe ara wọn lọ́ṣọ̀ọ́, pẹ̀lú ìmọ̀wọ̀n ara ẹni àti àròjinlẹ̀,* kì í ṣe dídi irun lọ́nà àrà àti lílo wúrà tàbí péálì tàbí aṣọ olówó ńlá,+ 10 àmọ́ kó jẹ́ lọ́nà tó yẹ àwọn obìnrin tó sọ pé àwọn ń sin Ọlọ́run tọkàntọkàn,+ ìyẹn nípa àwọn iṣẹ́ rere.

11 Kí obìnrin kẹ́kọ̀ọ́ ní ìdákẹ́jẹ́ẹ́* kó sì máa tẹrí ba délẹ̀délẹ̀.+ 12 Mi ò fọwọ́ sí kí obìnrin kọ́ni tàbí kó pàṣẹ lé ọkùnrin lórí, àmọ́ kí ó dákẹ́.*+ 13 Torí Ádámù ni Ọlọ́run kọ́kọ́ dá, kó tó wá dá Éfà.+ 14 Bákan náà, a kò tan Ádámù jẹ, àmọ́ a tan obìnrin náà jẹ pátápátá,+ ó sì di arúfin. 15 Síbẹ̀, ọmọ bíbí máa dáàbò bò ó,+ tó* bá rọ̀ mọ́ ìgbàgbọ́ àti ìfẹ́ àti ìjẹ́mímọ́ àti àròjinlẹ̀.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́