ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Émọ́sì 1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Émọ́sì

      • Émọ́sì gba iṣẹ́ kan látọ̀dọ̀ Jèhófà (1, 2)

      • Ìdájọ́ lórí ìdìtẹ̀ tó ń wáyé (3-15)

        • Síríà (3-5), Filísíà (6-8), Tírè (9, 10), Édómù (11, 12), Ámónì (13-15)

Émọ́sì 1:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Ẹrù” tàbí “Gbé Ẹrù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 11:5, 6
  • +2Kr 26:1, 3, 4; Ais 1:1
  • +2Ọb 14:23, 24; Ho 1:1; Emọ 7:10
  • +2Ọb 13:10, 11
  • +Sek 14:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2004, ojú ìwé 10

Émọ́sì 1:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 33:9; Na 1:4

Émọ́sì 1:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìwà ọ̀daràn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 8:12; 10:32, 33; 13:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2004, ojú ìwé 16

Émọ́sì 1:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 19:15
  • +Jer 49:27

Émọ́sì 1:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn tó ń di ọ̀pá àṣẹ mú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 7:8; 8:4; 17:1
  • +2Ọb 16:9

Émọ́sì 1:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 25:15
  • +2Kr 21:16, 17; 28:18; Joẹ 3:4, 6

Émọ́sì 1:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 25:17, 20; 47:1; Sek 9:5

Émọ́sì 1:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn tó ń di ọ̀pá àṣẹ mú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 20:1
  • +Jer 47:5
  • +Sef 2:4
  • +Ais 14:29; Jer 47:4; Isk 25:16, 17; Sef 2:5; Sek 9:6

Émọ́sì 1:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 26:2
  • +Joẹ 3:4, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ọjọ́ Jèhófà, ojú ìwé 111

Émọ́sì 1:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 26:12

Émọ́sì 1:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joẹ 3:19
  • +Isk 25:12
  • +2Kr 28:17; Ọbd 10

Émọ́sì 1:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 36:10, 11; Ọbd 9
  • +Ais 34:5, 6; Jer 49:13

Émọ́sì 1:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 25:3; Sef 2:8
  • +Ond 11:12, 13; Jer 49:1

Émọ́sì 1:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 49:2; Isk 25:5

Émọ́sì 1:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 27:2, 3; 49:3

Àwọn míì

Émọ́sì 1:12Kr 11:5, 6
Émọ́sì 1:12Kr 26:1, 3, 4; Ais 1:1
Émọ́sì 1:12Ọb 14:23, 24; Ho 1:1; Emọ 7:10
Émọ́sì 1:12Ọb 13:10, 11
Émọ́sì 1:1Sek 14:5
Émọ́sì 1:2Ais 33:9; Na 1:4
Émọ́sì 1:32Ọb 8:12; 10:32, 33; 13:7
Émọ́sì 1:41Ọb 19:15
Émọ́sì 1:4Jer 49:27
Émọ́sì 1:52Ọb 16:9
Émọ́sì 1:5Ais 7:8; 8:4; 17:1
Émọ́sì 1:6Isk 25:15
Émọ́sì 1:62Kr 21:16, 17; 28:18; Joẹ 3:4, 6
Émọ́sì 1:7Jer 25:17, 20; 47:1; Sek 9:5
Émọ́sì 1:8Ais 20:1
Émọ́sì 1:8Jer 47:5
Émọ́sì 1:8Sef 2:4
Émọ́sì 1:8Ais 14:29; Jer 47:4; Isk 25:16, 17; Sef 2:5; Sek 9:6
Émọ́sì 1:9Isk 26:2
Émọ́sì 1:9Joẹ 3:4, 6
Émọ́sì 1:10Isk 26:12
Émọ́sì 1:11Joẹ 3:19
Émọ́sì 1:11Isk 25:12
Émọ́sì 1:112Kr 28:17; Ọbd 10
Émọ́sì 1:12Jẹ 36:10, 11; Ọbd 9
Émọ́sì 1:12Ais 34:5, 6; Jer 49:13
Émọ́sì 1:13Isk 25:3; Sef 2:8
Émọ́sì 1:13Ond 11:12, 13; Jer 49:1
Émọ́sì 1:14Jer 49:2; Isk 25:5
Émọ́sì 1:15Jer 27:2, 3; 49:3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Émọ́sì 1:1-15

Émọ́sì

1 Ọ̀rọ̀ Émọ́sì,* ọ̀kan lára àwọn tó ń sin àgùntàn láti Tékóà,+ èyí tó gbọ́ nínú ìran nípa Ísírẹ́lì nígbà ayé Ùsáyà+ ọba Júdà àti nígbà ayé Jèróbóámù+ ọmọ Jóáṣì,+ ọba Ísírẹ́lì, ní ọdún méjì ṣáájú ìmìtìtì ilẹ̀ tó wáyé.+ 2 Ó sọ pé:

“Jèhófà yóò ké ramúramù láti Síónì,

Yóò sì gbé ohùn rẹ̀ sókè láti Jerúsálẹ́mù.

Ibi ìjẹko àwọn olùṣọ́ àgùntàn máa ṣọ̀fọ̀,

Ewéko orí òkè Kámẹ́lì á sì gbẹ dà nù.”+

 3 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,

‘“Nítorí ìdìtẹ̀* mẹ́ta Damásíkù àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,

Nítorí wọ́n fi ohun èlò ìpakà onírin pa Gílíádì bí ọkà.+

 4 Torí náà, màá rán iná sí ilé Hásáẹ́lì,+

Á sì jó àwọn ilé gogoro tó láàbò ti Bẹni-hádádì run.+

 5 Màá ṣẹ́ ọ̀pá ìdábùú ẹnubodè Damásíkù;+

Màá sì pa àwọn tó ń gbé Bikati-áfénì run

Àti àwọn tó ń ṣàkóso* ní Bẹti-édẹ́nì;

Àwọn èèyàn Síríà sì máa lọ sí ìgbèkùn ní Kírì,”+ ni Jèhófà wí.’

 6 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,

‘“Nítorí ìdìtẹ̀ mẹ́ta ti Gásà+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,

Nítorí wọ́n kó gbogbo àwọn èèyàn nígbèkùn,+ wọ́n sì fà wọ́n lé Édómù lọ́wọ́.

 7 Torí náà, màá rán iná sí ògiri Gásà,+

Á sì jó àwọn ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò run.

 8 Màá pa àwọn tó ń gbé Áṣídódì run,+

Àti àwọn tó ń ṣàkóso* ní Áṣíkẹ́lónì;+

Màá fìyà jẹ Ẹ́kírónì,+

Àwọn Filísínì tó ṣẹ́ kù yóò sì ṣègbé,”+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.’

 9 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,

‘Nítorí ìdìtẹ̀ mẹ́ta Tírè+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,

Nítorí wọ́n kó gbogbo àwọn tí wọ́n mú nígbèkùn, wọ́n sì fà wọ́n lé Édómù lọ́wọ́,

Àti nítorí pé wọn kò rántí májẹ̀mú àwọn arákùnrin.+

10 Torí náà, màá rán iná sí ògiri Tírè,

Á sì jó àwọn ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò run.’+

11 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,

‘Nítorí ìdìtẹ̀ mẹ́ta Édómù+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,

Nítorí ó fi idà lépa arákùnrin rẹ̀,+

Àti nítorí pé ó kọ̀ láti ṣàánú rẹ̀;

Ó ń fi ìbínú rẹ̀ fà wọ́n ya láìdáwọ́ dúró,

Kò sì yéé bínú sí wọn.+

12 Torí náà, màá rán iná sí Témánì,+

Á sì jó àwọn ilé gogoro tó láàbò ti Bósírà run.’+

13 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,

‘“Nítorí ìdìtẹ̀ mẹ́ta àwọn ọmọ Ámónì+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,

Nítorí wọ́n la inú àwọn aboyún Gílíádì kí wọ́n lè mú agbègbè tiwọn fẹ̀ sí i.+

14 Torí náà, màá sọ iná sí ògiri Rábà,+

Á sì jó àwọn ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò run,

Ariwo á sọ ní ọjọ́ ogun,

Àti ìjì líle ní ọjọ́ ẹ̀fúùfù.

15 Ọba wọn á sì lọ sí ìgbèkùn pẹ̀lú àwọn ìjòyè rẹ̀,”+ ni Jèhófà wí.’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́