ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 110
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sáàmù

      • Ọba àti àlùfáà bíi ti Melikisédékì

        • ‘Máa jọba láàárín àwọn ọ̀tá rẹ’ (2)

        • Àwọn ọ̀dọ́ tó yọ̀ǹda ara wọn dà bí ìrì tó ń sẹ̀ (3)

Sáàmù 110:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 8:34; Ef 1:20; Heb 8:1; 12:2
  • +Mt 22:43, 44; Mk 12:36; Lk 20:42, 43; Iṣe 2:34, 35; 1Kọ 15:25; Heb 1:3, 13; 10:12, 13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 252

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 194

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2012, ojú ìwé 26

    9/1/2006, ojú ìwé 13-14

    6/1/1994, ojú ìwé 28-29

    Ìmọ̀, ojú ìwé 96

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 22

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 85-87, 176

Sáàmù 110:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 2:8, 9; 45:4, 5; Mt 28:18; Ifi 6:2; 12:5; 19:11, 15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 85-87

Sáàmù 110:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ní ọjọ́ tí àwọn ọmọ ogun rẹ kóra jọ.”

  • *

    Ní Héb., “láti ilé ọlẹ̀ ọ̀yẹ̀.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 55

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 61-65

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2008, ojú ìwé 12

    9/15/2002, ojú ìwé 8

Sáàmù 110:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “yí ìpinnu rẹ̀ pa dà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 7:21, 28
  • +Jẹ 14:18; Heb 5:5, 6; 6:19, 20; 7:3, 11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 194

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2012, ojú ìwé 26

    9/1/2006, ojú ìwé 14

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 107

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 85-87, 154

Sáàmù 110:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 16:8
  • +Sm 2:2; Ro 2:5; Ifi 11:18; 19:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2006, ojú ìwé 14

Sáàmù 110:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “láàárín.”

  • *

    Ní Héb., “olórí.”

  • *

    Tàbí “gbogbo ayé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 79:6
  • +Jer 25:31-33

Sáàmù 110:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó ń tọ́ka sí “Olúwa mi” inú ẹsẹ 1.

Àwọn míì

Sm 110:1Ro 8:34; Ef 1:20; Heb 8:1; 12:2
Sm 110:1Mt 22:43, 44; Mk 12:36; Lk 20:42, 43; Iṣe 2:34, 35; 1Kọ 15:25; Heb 1:3, 13; 10:12, 13
Sm 110:2Sm 2:8, 9; 45:4, 5; Mt 28:18; Ifi 6:2; 12:5; 19:11, 15
Sm 110:4Heb 7:21, 28
Sm 110:4Jẹ 14:18; Heb 5:5, 6; 6:19, 20; 7:3, 11
Sm 110:5Sm 16:8
Sm 110:5Sm 2:2; Ro 2:5; Ifi 11:18; 19:19
Sm 110:6Sm 79:6
Sm 110:6Jer 25:31-33
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sáàmù 110:1-7

Sáàmù

Ti Dáfídì. Orin.

110 Jèhófà sọ fún Olúwa mi pé:

“Jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi+

Títí màá fi fi àwọn ọ̀tá rẹ ṣe àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.”+

 2 Jèhófà yóò na ọ̀pá agbára rẹ jáde láti Síónì, yóò sọ pé:

“Máa ṣẹ́gun lọ láàárín àwọn ọ̀tá rẹ.”+

 3 Àwọn èèyàn rẹ máa yọ̀ǹda ara wọn tinútinú ní ọjọ́ ìjáde ogun rẹ.*

Nínú ọlá ńlá ìjẹ́mímọ́, láti ibi tí ọ̀yẹ̀ ti ń là,*

O ní àwùjọ àwọn ọ̀dọ́ tí wọ́n rí bí ìrì tó ń sẹ̀.

 4 Jèhófà ti búra, kò sì ní pèrò dà,* ó ní:

“Ìwọ jẹ́ àlùfáà títí láé+

Ní ọ̀nà ti Melikisédékì!”+

 5 Jèhófà yóò wà ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ;+

Yóò fọ́ àwọn ọba túútúú ní ọjọ́ ìbínú rẹ̀.+

 6 Yóò mú ìdájọ́ ṣẹ lórí* àwọn orílẹ̀-èdè;+

Yóò fi òkú kún ilẹ̀ náà.+

Yóò fọ́ aṣáájú* ilẹ̀ fífẹ̀* túútúú.

 7 Yóò* mu omi odò tó wà lójú ọ̀nà,

Yóò sì gbé orí rẹ̀ sókè.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́