ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kọ́ríńtì 5
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Kọ́ríńtì

      • Gbígbé ibùgbé ọ̀run wọ̀ (1-10)

      • Iṣẹ́ òjíṣẹ́ ìpadàrẹ́ (11-21)

        • Ẹ̀dá tuntun (17)

        • Ikọ̀ fún Kristi (20)

2 Kọ́ríńtì 5:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “yọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Pe 1:13, 14
  • +1Kọ 15:50; Flp 3:20, 21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/1998, ojú ìwé 15

    3/1/1995, ojú ìwé 30

2 Kọ́ríńtì 5:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ibùgbé.”

  • *

    Tàbí “gbé ibùgbé wa.”

  • *

    Tàbí “ibùgbé wa ọ̀run.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 6:5; 8:23; 1Kọ 15:48, 49

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/1998, ojú ìwé 15

2 Kọ́ríńtì 5:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/1998, ojú ìwé 15

2 Kọ́ríńtì 5:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 15:43, 44; Flp 1:21
  • +1Pe 1:3, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2020, ojú ìwé 23

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 18

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/1998, ojú ìwé 15

2 Kọ́ríńtì 5:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àsansílẹ̀; ìdánilójú (ẹ̀jẹ́) ohun tó ń bọ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 2:10
  • +Ro 8:23; Ef 1:13, 14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 15-16

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/1998, ojú ìwé 15

2 Kọ́ríńtì 5:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 14:3

2 Kọ́ríńtì 5:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2005, ojú ìwé 16-20

    1/15/1998, ojú ìwé 8-13

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    9/1996, ojú ìwé 1

2 Kọ́ríńtì 5:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Flp 1:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/1998, ojú ìwé 15

    3/1/1995, ojú ìwé 30

2 Kọ́ríńtì 5:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fara hàn kedere.”

  • *

    Tàbí “ibi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 22:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/1998, ojú ìwé 15-16

2 Kọ́ríńtì 5:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “a ò pa mọ́ fún Ọlọ́run.”

  • *

    Tàbí “a ò pa mọ́ fún ẹ̀rí ọkàn ẹ̀yin náà.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/1998, ojú ìwé 15-16

2 Kọ́ríńtì 5:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 10:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/1998, ojú ìwé 16

2 Kọ́ríńtì 5:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 11:1, 16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/1998, ojú ìwé 16

2 Kọ́ríńtì 5:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 53:10; Mt 20:28; 1Ti 2:5, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 10-11

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2010, ojú ìwé 9

    5/15/2010, ojú ìwé 27

    3/15/2005, ojú ìwé 14

    12/15/1998, ojú ìwé 16

    6/15/1995, ojú ìwé 14-15

    6/1/1994, ojú ìwé 15-16

    2/15/1992, ojú ìwé 14-15

    Jí!,

    10/8/1996, ojú ìwé 27

    Yiyan, ojú ìwé 89

2 Kọ́ríńtì 5:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 14:7, 8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 28

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 10-11

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2010, ojú ìwé 9

    5/15/2010, ojú ìwé 27

    3/15/2005, ojú ìwé 14

    12/15/1998, ojú ìwé 16-17

    2/15/1992, ojú ìwé 14-15

2 Kọ́ríńtì 5:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 12:50
  • +Jo 20:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2008, ojú ìwé 28

    12/15/1998, ojú ìwé 16-17

2 Kọ́ríńtì 5:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ga 6:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/1998, ojú ìwé 17

    1/1/1993, ojú ìwé 5-6

2 Kọ́ríńtì 5:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 5:10; Ef 2:15, 16; Kol 1:19, 20
  • +Iṣe 20:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2014, ojú ìwé 18

    12/15/2010, ojú ìwé 12-14

    12/15/1998, ojú ìwé 17-18

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 209-210

2 Kọ́ríńtì 5:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 5:6; 1Jo 2:1, 2
  • +Ro 4:25; 5:18
  • +Mt 28:19, 20; Iṣe 13:38, 39

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2010, ojú ìwé 12-13

    12/15/1998, ojú ìwé 17-18

2 Kọ́ríńtì 5:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 6:19, 20
  • +Flp 3:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 51-53

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2010, ojú ìwé 12-14

    11/1/2002, ojú ìwé 16

    12/15/1998, ojú ìwé 18

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 58-60, 64, 67

2 Kọ́ríńtì 5:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 4:15; 7:26
  • +Ro 1:16, 17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2000, ojú ìwé 18-19

    12/15/1998, ojú ìwé 18

Àwọn míì

2 Kọ́r. 5:12Pe 1:13, 14
2 Kọ́r. 5:11Kọ 15:50; Flp 3:20, 21
2 Kọ́r. 5:2Ro 6:5; 8:23; 1Kọ 15:48, 49
2 Kọ́r. 5:41Kọ 15:43, 44; Flp 1:21
2 Kọ́r. 5:41Pe 1:3, 4
2 Kọ́r. 5:5Ef 2:10
2 Kọ́r. 5:5Ro 8:23; Ef 1:13, 14
2 Kọ́r. 5:6Jo 14:3
2 Kọ́r. 5:8Flp 1:23
2 Kọ́r. 5:10Ifi 22:12
2 Kọ́r. 5:122Kọ 10:10
2 Kọ́r. 5:132Kọ 11:1, 16
2 Kọ́r. 5:14Ais 53:10; Mt 20:28; 1Ti 2:5, 6
2 Kọ́r. 5:15Ro 14:7, 8
2 Kọ́r. 5:16Mt 12:50
2 Kọ́r. 5:16Jo 20:17
2 Kọ́r. 5:17Ga 6:15
2 Kọ́r. 5:18Ro 5:10; Ef 2:15, 16; Kol 1:19, 20
2 Kọ́r. 5:18Iṣe 20:24
2 Kọ́r. 5:19Ro 5:6; 1Jo 2:1, 2
2 Kọ́r. 5:19Ro 4:25; 5:18
2 Kọ́r. 5:19Mt 28:19, 20; Iṣe 13:38, 39
2 Kọ́r. 5:20Ef 6:19, 20
2 Kọ́r. 5:20Flp 3:20
2 Kọ́r. 5:21Heb 4:15; 7:26
2 Kọ́r. 5:21Ro 1:16, 17
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
2 Kọ́ríńtì 5:1-21

Ìwé Kejì sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì

5 Nítorí a mọ̀ pé tí ilé wa ní ayé bá wó,*+ ìyẹn àgọ́ yìí, Ọlọ́run máa fún wa ní ilé míì, ilé tí a kò fi ọwọ́ kọ́,+ tó jẹ́ ti ayérayé ní ọ̀run. 2 Nítorí à ń kérora nínú ilé* yìí lóòótọ́, ó sì ń wù wá gan-an pé ká gbé èyí tó wà fún wa* láti ọ̀run* wọ̀,+ 3 kí ó lè jẹ́ pé, nígbà tí a bá gbé e wọ̀, a ò ní wà ní ìhòòhò. 4 Kódà, àwa tí a wà nínú àgọ́ yìí ń kérora, ìdààmú bò wá mọ́lẹ̀, torí pé a ò fẹ́ bọ́ èyí kúrò, àmọ́ a fẹ́ gbé èkejì wọ̀,+ kí ìyè lè gbé èyí tó lè kú mì.+ 5 Ọlọ́run ni ẹni tó múra wa sílẹ̀ fún ohun yìí gan-an,+ ó fún wa ní ẹ̀mí láti fi ṣe àmì ìdánilójú ohun tó ń bọ̀.*+

6 Nítorí náà, a jẹ́ onígboyà nígbà gbogbo, a sì mọ̀ pé nígbà tí ilé wa ṣì wà nínú ara yìí, a kò sí lọ́dọ̀ Olúwa,+ 7 nítorí à ń rìn nípa ìgbàgbọ́, kì í ṣe nípa ohun tí à ń rí. 8 A jẹ́ onígboyà, ó sì tẹ́ wa lọ́rùn pé kí a má ṣe wà nínú ara, kí a sì fi ọ̀dọ̀ Olúwa ṣe ilé wa.+ 9 Torí náà, bóyá a wà nílé pẹ̀lú rẹ̀ àbí a ò sí lọ́dọ̀ rẹ̀, ohun tí a fẹ́ ni pé kó tẹ́wọ́ gbà wá. 10 Nítorí gbogbo wa ló máa fara hàn* níwájú ìjókòó ìdájọ́ Kristi, kí kálukú lè gba èrè àwọn ohun tó ṣe nígbà tó wà nínú ara, ì báà jẹ́ rere tàbí búburú.*+

11 Torí náà, nígbà tí a ti mọ ohun tí ìbẹ̀rù Olúwa jẹ́, à ń yí àwọn èèyàn lérò pa dà, àmọ́ Ọlọ́run mọ̀ wá dáadáa.* Síbẹ̀, mo lérò pé ẹ̀rí ọkàn ẹ̀yin náà mọ̀ wá dáadáa.* 12 Kì í ṣe pé a tún ń dámọ̀ràn ara wa fún yín, àmọ́ à ń fún yín ní ohun tí á mú kí ẹ máa fi wá yangàn, kí ẹ lè rí nǹkan sọ fún àwọn tó ń fi ohun tó wà lóde yangàn,+ tí kì í ṣe ohun tó wà nínú ọkàn. 13 Tí orí wa bá yí,+ nítorí Ọlọ́run ni; tí orí wa bá pé, nítorí tiyín ni. 14 Nítorí ìfẹ́ tí Kristi ní sọ ọ́ di dandan fún wa, torí ohun tí a ti pinnu nìyí, pé ọkùnrin kan kú fún gbogbo èèyàn;+ nípa bẹ́ẹ̀, gbogbo wọn ti kú. 15 Ó sì kú fún gbogbo wọn kí àwọn tó wà láàyè má ṣe tún wà láàyè fún ara wọn mọ́,+ bí kò ṣe fún ẹni tó kú fún wọn, tí a sì gbé dìde.

16 Nítorí náà, láti ìsinsìnyí lọ, a ò fojú tara wo ẹnikẹ́ni mọ́.+ Bí a tilẹ̀ ń fojú tara wo Kristi tẹ́lẹ̀, ó dájú pé a ò fojú yẹn wò ó mọ́.+ 17 Nítorí náà, tí ẹnikẹ́ni bá wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi, ó ti di ẹ̀dá tuntun; àwọn ohun àtijọ́ ti kọjá lọ;+ wò ó! àwọn ohun tuntun ti dé. 18 Àmọ́ ohun gbogbo wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run, ẹni tó tipasẹ̀ Kristi mú wa pa dà bá ara rẹ̀ rẹ́,+ tó sì fún wa ní iṣẹ́ òjíṣẹ́ ìpadàrẹ́,+ 19 ìyẹn ni pé Ọlọ́run mú ayé kan pa dà bá ara rẹ̀ rẹ́ nípasẹ̀ Kristi,+ kò ka àwọn àṣemáṣe wọn sí wọn lọ́rùn,+ ó sì fi ọ̀rọ̀ ìpadàrẹ́ sí ìkáwọ́ wa.+

20 Nítorí náà, a jẹ́ ikọ̀+ tó ń dípò fún Kristi,+ bíi pé Ọlọ́run ń pàrọwà nípasẹ̀ wa. Gẹ́gẹ́ bí ẹni tó ń dípò fún Kristi, a bẹ̀bẹ̀ pé: “Ẹ pa dà bá Ọlọ́run rẹ́.” 21 Ẹni tí kò mọ ẹ̀ṣẹ̀+ ni ó sọ di ẹ̀ṣẹ̀* fún wa, kí a lè di olódodo lójú Ọlọ́run nípasẹ̀ rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́